Aworawo pelu itumo

Aworawo pelu itumo Contact information, map and directions, contact form, opening hours, services, ratings, photos, videos and announcements from Aworawo pelu itumo, Astrologist & Psychic, Ilorin, Ibadan.

FUN IWADI LORI IRAWO ATI AKOSEJAYE MESSAGE ME ON WHATSAPP 09060661028


WHATSAPP CHANNEL πŸ‘‡πŸ‘‡πŸ‘‡

https://whatsapp.com/channel/0029VbBJZlj0G0XoszYZJo3a

Facebook link πŸ”—πŸ‘‡πŸ‘‡πŸ‘‡


https://m.facebook.com/groups/894293812838190/?ref=share&mibextid=NSMWBT

ASIRI TO WA LARIN  IRAWO INA ATI IRAWO OMIIRAWO OMIIrawo yi pinsi metaIrawo omi agbara ( cancer πŸ¦€) Irawo omi tutu (Scorp...
30/08/2026

ASIRI TO WA LARIN IRAWO INA ATI IRAWO OMI

IRAWO OMI

Irawo yi pinsi meta

Irawo omi agbara ( cancer πŸ¦€)
Irawo omi tutu (Scorpio ♏️)
Irawo omi tikiru (Pisces 🐟)

Awon oni irawo yi je alagbara eda akanda eledumare ni won, ololufe awon eniyan ni wonje, aiye ma ngba ti won ni gbogbo ibi ti won ba de, ogun dudu ki sise fun apakan ninu won, alaje ni opolopo won, ogo agbaiye ni won tori celebrity ni o poju ninu won, opolopo won ama se irin ajo losi oke okun, awon irawo yi nise pelu spirituality toripe emi airi ma saba wa pelu won, opolopo won si je omo elegbe, olohun situn fun won ni spiritual power bi ki emi ma ba won soro olohun situn fun won ni oju ala(dreams) pupo, opolopo won ni ogun idile ma nbaja ati isoro ile oko pupo ninu awon obinrin inu won ni won ki ri ile oko gbe toripe won ma nrewa pupo leyi toma nfun opolopo won ni anfani latima se sina, won situn ni agbara ibalopo.
awon ota ma nsi opolopo won ni ona leyi toma nfa ewo jije funwon,awon nkan to ma nfa ki irin ajo aiye won fi ma ndaru niyen, awon irawo yi gbodo ma se igbinyanju dada ati adura ki won le ba tete de ibi ti won lo laiye.

IRAWO INA

Irawo yi pinsi meta

Irawo ina Aries 🐏
Irawo ina Leo 🦁
Irawo ina Sagittarius ♐️

irawo yi je okan pataki ninu awon irawo yoku irawo yi ni agbara pupo awon irawo yi je olokiki ati olorire eda, ninu ebun tia fun onirawo yi ni opolo, ojogbon ni opolopo won je, oninu rere ni won je, eni ti olohun yio sanu nipa owo nini, won ma tete ni owo afi eyi ti ogun aiye ba nda lamu loku, won je eda to la wo(generous) pupo , won oma pe owo kan ni akin na, inakuna (extravagant) won po, oni irawo yi ti obafe ni akojo kio so owo na, awon irawo yi ni amo si imole tio tan ina sinu okunkun.
akikanju,onigboya, alagidi, alaigboro eniyan ni won je, ogun dudu ma nsise fun awon onirawo yi dada bi ogun ti won bajo ni ori ina, awon onirawo yi won gbodo mase igbinyanju dada ki won leba ri ogo won.

ASIRI TO WA LARIN IRAWO INA ATI IRAWO OMI

Awon irawo yi kole fe arawon toripe omi ni onpa oro ina, ibagbepo won ko rorun rara ti awon irawo omi yi ba ferawon nkan koni lodede funwon rara, ija ati aigbo ara eni ye ni yio ma sele ni arin won nkan ko ni lo dede ni arin won, ki onirawo ina sora fun sina sise pelu irawo omi toripe ifaseyin ni, koda kio ni aje lara kodara afi ti awon mejeji ba jo je omo omi loku.

IRAWO INA ARIES 🐏
Ama irawo kan wa ninu awon irawo ina tio le fe irawo omi meteta irawo yi na ni anpe ni irawo ina Aries 🐏 ama awon irawo ina yoku kogbodo danwon ti won obafe wahala, irawo ina Aries nikan lolefe irawo omi pelu majemu kan sikeji , isesi irawo ina Aries yato si awon irawo ina toku toripe irawo yi wani ati ara irawo meji ti anpe ni irawo omi tutu Scorpio ♏️ ati irawo ina Leo 🦁 .
ara awon irawo mejeji yi ni irawo ina Aries 🐏 ti jade omi ni npa oro ina amo bi ti ina Aries 🐏 ko toripe ina tio nsan bi omi ni .nkan ti ofi ni afani lati fe irawo omi ni yen ama ewu situn wa nibe fun irawo yi nigba ti irawo yi ba pe omo 35 years asiko eewu ni asiko yi je fun irawo Aries 🐏 ti o ba fe irawo omi toripe yi o ti re ina ogo re, nkan koni felo dede ma, afi ki irawo ina Aries 🐏 ko gbiyanju lati fe irawo afefe kio leba ma ba fe ina ogo re jo si oke, afi ti awon meji baje omo elegbe omi ni ko fi ni si wahala larin won.

NOTE ki awon onirawo ina yoku ma danwon tabi kiwon gbinyanju latife irawo omi abi pe won tie fe bawon ni ajosepo , kiwon ma danwon rara ti wonko bafe wahala.

FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

AJE ARA IRAWO OMI TIKIRU PISCES ♓️ PART 2Irawo omi tikiru je irawo aje, irawo ola, irawo okiki, Awon oni irawo olohun ma...
29/08/2026

AJE ARA IRAWO OMI TIKIRU PISCES ♓️ PART 2

Irawo omi tikiru je irawo aje, irawo ola, irawo okiki,

Awon oni irawo olohun ma ntete la ona owo fun won ni aaro aiye won, afi eniyan ti owo aiye ba nbe ni arare ti awon agbalagba ba nda lamu abi iwo tie nse nkan eewo irawo re ati akosejaiye re , iru eniyan be yio lefun lati ri aje ara re lo afi tio balo se atunse nikan loku.

Akanda eledumare ni awon oni irawo yi je ,
95% ninu awon oni irawo yi ni won ni egbe

Osepataki fun awon oni irawo yi ki won ma toju awon egbe won ki won ma ba damu pupo laiye, toripe iwo ti oba ma nse etutu fun awon egbe re, awon egbere won o ma ranwonlo lori gbogbo adawole re , iru eniyan be koni ma inira owo rara.

ama iwo ti o ba kin toju awon egbe re ti o fun awon egbe re ni eewo je iru eniyanbe nkan yio ma daru fun ni , nkan koni lodede fun rara toripe awon toye kiwon ma ranwonlo lori gbogbo adawole re ni won ti ko eyin sio yen, ki wani ona abayo si fun iwo ti awon egbe re bati ko eyin sio, lose iwadi nipa iru egbe ti owa, kio leba mo nkan ti wa fi se etutu fun won ti won fi ma ranwonlo pada.

AJE ARA IRAWO OMI TIKIRU PISCES ♓️

aje olokun a*oro dayo oguguluso oni iso iboji
Wafi ilemi se ibujoko wafi odede mi se ibugbe

Iseda olokun aje ni awon oni irawo yi ma nsaba je toripe ninu irawo ti olokun aje tin ma jade ni irawo omi tikiru Pisces ♓️ wa.

Iru awon iseda bayi iranse olohun ni won ma nje toripe olohun ma nran won si idile ti oba wu, lati wa so won di olowo ati olola.

Iseda olokun yi je iseda aje dandan ni owo ni odo won, iru awon iseda bayi kogbodo ma rahun owo ran abi ki won tie ma se aroye owo, iwo ti oba je iseda olokun ti ona owo ba dimo abi nkan kotie lodede fun o rara, lo se awari arare dada toripe ogun ti won ninu aiye re o, toripe eran arare owo ni, okinse eniyan toye kio ma se whala ko to ri owo.

Alagbara ni awon iseda yi je idile ti iru awon iseda bayi baya idile na kotun tosi mo laiye.

Dandan ni fun awon oni irawo yi ki won ma bo aje ara won ki won leba ri aje ara won lo , toripe aje arawon gba amojuto toripe aje ara won kopamo rara, ororun fun awon alagbara ika lati gba aje ara won.

Pupo ninu awon oni irawo yi ni awon alagbara ika ti gba aje ara won, leyi to nse okunfa ki won ma damu kakiri ti won sin se wahala kiwon tori owo.

Oni irawo yi tiki ba se etutu aje arare iru eniyan be yio lefun lati ri aje ara re, toripe dandan ni fun awon oni irawo yi lati ma bo aje ara won ki aje ara won leba ma sise fun won.

Elomiran nkan tose okufa airi aje lo fun elomiran ni wipe ko bo aje ara re.

KINI OKUNFA AIRI AJE LO FUN ONI IRAWO OMI TIKIRU PISCES ♓️

Ti awon agbalagba ba ndamu oni irawo yi abi owo awon agbalagba ni owa ni ara re, yio le fun oni irawo yi lati ri aje arare lo, afi kolose etutu awon agbalagba kio leba ri aje arare lo.

Ti oni irawo yi ba nfun awon eegbe re ni eewo je to nse nkan totako ofin ati ilana awon egbere iru eniyan be yio lefun lati ri aje arare lo, ki iru eniyan be lose iwadi nipa iru egbe ti owa kio sise etutu fun won kio leba ri aje arare lo.

Ti eniyan ba nse nkan totako irawo re ati akosejaiye re abi onfun irawo re ati akosejaiye re ni eewo je iru eniyan be yio lefun lati ri aje arare lo,

elomiran wa toje wipe ogun aiye kan kose eewo irawo re ati akosejaiye re nin nse ni nkan fi daru fun, iwona se iwadi nipa irawore ati akosejaye kio leba ma ibi ti ogun tin ja o ati ona abayo si kio ma ba wa aiye lasan.

Ti oni irawo yi koba kin bo aje arare yio lefun oni irawo yi lati ri aje arare lo, iwona lose iwadi nipa aje arare ati awon nkan ti wa fi se etutu fun aje arare kio leba ri aje arare lo.

asiri po ni abe irawo yi ti akolesotan iwoni kio se iwadi nipa arare kio leba mo iru ogun tin ja o ati ona abayo si kio maba mase wahala lasan, ki irin ajo odun kan maba di odun mewa mo lowo.

FUN IWADI LORI IRAWO RE ATI AKOSEJAYE RE ABI IWO WA NINU ISORO KAN SIKEJI TO NWA ONA ABAYO SI MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

IRAWO ERUPE ERUKU ( CAPRICORN )(DECEMBER 22- JANUARY 19) PART ONE 1 planet tonje oba Irawo yi ni (Saturn ) oba ni awon i...
29/08/2026

IRAWO ERUPE ERUKU ( CAPRICORN )
(DECEMBER 22- JANUARY 19) PART ONE 1

planet tonje oba Irawo yi ni (Saturn ) oba ni awon irawo yi je (the king) olori ni awon oni irawo yi ma nje ni gbogbo ibi ti won bade, awon oni irawo yi je akanda eniyan, awon agbalagba omo situn ma npo ninu won, elemi gigun eniyan ni won ma nje laiye, emi won ma ngun gan laiye,ajidewe situn wa funwon, pupo ninu awon oni irawo yi biwon ba nse ndagba si be nani won ma kekere loju,

Asiwaju eniyan ni won je agidi okan po funwon,won asitun mabinu pupo,ama nkan ma ntete tan ni okan won, olotito eniyan ni won je tori olokan diduro shinshin lori ipinu won, alanu eniyan niwon, won ma nsanu omo lakeji ti koba ni towon.

Awon oni irawo yije eniyan to ni ifarada ati emi iforiti , awon oni irawo yi korira iyipada, oni irawo yi je akikanju akoni (Hero) ni won je.

Ninu awon irawo tiwon ma nri wahala ati isoro laiye ni awon irawo yi wa, pupo ninu awon oni irawo yi niwon ma nse opolopo whala ni aro aiye won ki olohun to sanu won, pupo ninu won niwon ma nsina kiwon to mo oju ona latara aimo nipa asiri irawo won ati akosejaiye won.

ose pataki fun gbogbo irawo lati loma nipa irawo re ati akosejaiye kio le ba tete ri ona lo.

ori (head) adawon ni awon oni irawo yi yan, kosi eniyan ti abi si abe irawo yi ti ko ni ri adanwo afi eniti oba je oni igbinyanju , aladura ati oni sara lori oro aye re ni eyi ti oba irawo re mu ati akosejaiye re mu ni yio tete ri ona lo ninu irin ajo aiye re.

Ologo eniyan alaje eniyan ni won je, awon oni irawo won ko gbodo se ole (laze) rara, won ko gbogbodo yanbo ise rara toripe ninu oogun won ni won o ti la laiye, won kin saba ri eniyan ran won lowo afi ki won mu oju to ise owo won dada ki won leba tete ni akojo laiye.

Oba ni irawo yi je, leyin opolopo whala ati idamu, ola ti olohun ma da won ni aiye bi ti oba ni , ti won o si pada wa dari opolopo awon eniyan.

Awon oni irawo yi ma ni idojuko awon agbalagba ogun idile situn ma nba won ja pupo toripe ori ade ni won je, ipo tiwon sima lo laiye bi ti oba ni, eyi ni o ma nfa ogun awon ota fun won ati ogun awon agbalagba toripe wonko nife kiwon je oba le awon lori, eyiyi ama fa tiwon ma nfise opolopo whala ati idamu laiye kiwon to ri ona lo, pupo ninu won gan ni awon ota ama ni agbara ju won lo, ogun ota si ma nbori pupo ninu won, afi eyiti oba je oni igbinyanju nipase kio loma nipa irawo ati akosejaye re tiwa fima bi wase rin irin ajo aiye re, iru eniyan beni yio tete jana, yio si tete bori ogun.

Ninu awon nkan tio ba irawo won mu ju ni adura wa ki won ma se adura dada ati sara ki won le ba tete ri ona lo laiye , sara sise fun awon eranko odi dandan fun won.

Ki awon oni irawo yi jinna si mimo se nkan eewo irawo won, kiwon maba fa whala ati idamu sinu irin ajo aiye won, toripe ninu awon nkan to lewu fun won ju ni ki won mase nkan totako irawo won ati akosejaiye won, ki awon oni irawo yi lom nipa ofin ati ilana irawo ati akosejaiye won, kiwon ma ba damu pupo laiye won.

Ogo idile ni won, olohun fun won ni emi ifura, olopolo pipe, oloye ni won.

Ki awon oni irawo yi ma se wa owo, ipo , ola , ni ona aito toripe ninu nkan totako irawo won ati kadara won ni owa, igbeyin iru eniyan be koni dara.

IGBEYAWO WON
Asife aya tabi oko ma nda pupo won lamu.

Awon obinrin inu won ma ni isoro ile oko tori
Igbeyawo pupo won ma ntuka latara asife aya ati oko, afi awon ti won ba lo mo nipa asiri irawo ati akosejaiye won , tiwon se iwadi dada lori eniyan tiwon fe fe ki won tofe arawon sile.

Whala ma npo fun awon oni irawo yi lati kekere won, debi wipe aiye gan ma nsu won, debi wipe won o ma ro ni okan arawon, bi awon oni irawo yi se yan kadara won wa lati orun wasi aiye ni yen, idajuko ma nwa fun won ni aro aiye won, afi eyi ti oba mu ojuto oro aiye re lati kekere ni yio tete ri ona abayo si oro aiye re .

FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

ASIRI TOWA LARI IRAWO INA ARIES β™ˆοΈ ATI IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️. IRAWO INA ARIES β™ˆοΈ NI AWON OMO TI ABI LATI (MARCH 21...
29/08/2026

ASIRI TOWA LARI IRAWO INA ARIES β™ˆοΈ ATI IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️.

IRAWO INA ARIES β™ˆοΈ NI AWON OMO TI ABI LATI (MARCH 21 - APRIL 21)
IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️ AWON OMO TI ABI LATI (AUGUST23 - SEPTEMBER 22)

Irawo erupe funfun Virgo ♍️ ati irawo ina Aries β™ˆοΈ je alagbara eda akanda eledumare ni won, akinkaju eniyan ni won asiwaju eniyan won je , apase eniyan ni won alaje eniyan ni won je, owo ma ntete ji si won lowo laro aiye won, pupo ninu won feren inakuna ki won soro fun ina kun na kin won leba ni akojo laiye won, awon irawo yi ma nni ota gan toripe awon eniyan ama binu ebun ti olohun fun won toripe won ma nju egbe won lo nibi gbogbo nkan eni esa sini won.

Awon oni irawo ma ni isoro lori igbeyawo, pupo ninu won ni won ma mu amubo oko ati aya, won situn ma nife irawo tiko ba irawo ti won mu ni eyi ti ole fa Wahala sinu aiye won.

Kipe dafun awon oni irawo tiko ba ni owo aiye ninu toripe olohun ama tete sanu won nipa owo ati ola ni aro aiye won, amo pupo ninu won ni won ma ni isoro awon eyele ni eyi ti koni je ki won teteri aje ara won lo, especially irawo erupe funfun Virgo ♍️ toripe asiri aje wa ni ara irawo yi , iwo omo virgo to bafe tete ri aje ara re lo, mojuto ara re dada ko leba tete ri aje arare lo

ASIRI TOWA LARI IRAWO INA ARIES β™ˆοΈ ATI IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️.

Ninu awon irawo ti won tako ara won ni won irawo mejeji wa, toripe awon irawo mejeje yi won kole fe ara won, toripe ibagbepo won koni rorun oni ija ola ija ni yio masele ni arin won aigbo ara eni ye yio ma sele ni arin.

Ti obinrin batun walo je irawo ina aries β™ˆοΈ obinrin yen ni yio ma pase ninu ile kosi nkan ti oko yen lese koni mase ni oju iyawo re.

Irawo erupe funfun Virgo ♍️ yio ma ri inira lati owo irawo ina Aries β™ˆοΈ irawo erupe funfun Virgo ♍️ koni fe gba inira ye ma ara eyiyi ni yio ma fa ija ni arin won ti won koba se suru fun ara won , eyiyi le fa opinya ni arin won ti won koba se suru larin ara won, ti awon mejeji ba nba ara won ja ni gbogbo igba eyiyi yio ma fa ifunpinpin owo ni arin won.

Ti irawo erupe funfun Virgo batun wa nse suru fun irawo ina aries β™ˆοΈ tiko fe baja irawo ina Aries β™ˆοΈ yio pada tan ni suru nani ni eyi ti ole pada jasi opinya larin won.

Idiwo owo yio ma sele larin awon mejeji, irawo ina aries β™ˆοΈ yio ma ri owo diedienitie, ama irawo erupe funfun Virgo koni ri owo rara toripe ti awon irawo mejeji bati fe arawon gbogbo aje irawo erupe funfun Virgo ♍️ ni yio di ti aries β™ˆοΈ ti yio si ma ba lo ajere toripe gbogbo ona ni irawo ina Aries fi ju irawo erupe funfun Virgo ♍️ lo abo irawo ni irawo erupe funfun Virgo ♍️ je , besini ako irawo ni irawo ina Aries β™ˆοΈ je tori idi eleyi irawo irawo aries ni yio ma pase ninu ile.

Eyi ti eba ba ara yin ni iru position bayi to je wipe eti fe ara yin sile ti ibagbepo yi kosi rorun rara elo ye akosejaiye yin won ibeni eti ri ona abayo si awon idojuko ti ndojuko ninu Igbeyawo yi.

AWON ISEDA TI WON LE FE ARA WON NINU AWON IRAWO YI.

awon iseda kan wa toje wipe won le fe ara won tiko sini si wahala ati idamu larin won.

Awon iseda wo ni, ohun ni awon ti won ba je omo elegbe ninu won toje wipe Inu egbe kan na ni wo ti jo wa , ti iru awon iseda yi ba pade ara won ti won fe ara won, koda ki irawo awon mejeji tako ara won ko ni si whala kan ninu irin ajo aiye won , toripe inu egbe kan nani won ti jo wa, ofin ati ilana ti egbe oyato si ti irawo gidigan toripe ti iku ba nsoro arun yio ma gbin ni beni oro egbe ati ti irawo se je.

AKIESI PATAKI :

Eleyi ni akiesi pataki fun gbogbo eniyan toba fe wo agbami ife kiwon ma fi irawo wiwo lasan fe ara won, kin won gbinyanju lati wo akosejaiye won na wo, ki won tofe arawon toripe ati akosejaiye ati irawo ni oye ki ema wo ki eto fe ara yin toripe melo awon ti irawo won papo tosije ibagbepo won korun rara whala ati idamu ni opada tu wonka.

BI irawo se sepataki be nani akosejaiye na sepataki, akosejaiye gan tun ma sepataki ju irawo lo nigba miran , ti eba ri awon irawo meji ti won fe ara won ti irawo won sitako arawon ti won sin ngbe igbe alafia larin won, kilo je o ribe asiri topamo si abe akosejaye won ni kadara lopa awon mejeji po ti won fin ngbe igbe irurun.

FUN IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

OMO ALAJE ATI AMIN IDAWON MON.Aje olokun a*o oro dayo, wafi ile mi se ibugbe wafi odede mi se ibujoko, aje ki ti aje ki ...
29/08/2026

OMO ALAJE ATI AMIN IDAWON MON.

Aje olokun a*o oro dayo, wafi ile mi se ibugbe wafi odede mi se ibujoko, aje ki ti aje ki te kin Ma ti kin ma te lawujo omo araiye.

Olohun to da gbogbo wa si ile aiye ti mo nkan ti yio wulo fun wa, kosisi eniyan ti olohun da si ile aiye tiko ni aje lara, boya oje omo elegbe nio abi okin se omo elegbe , ama aje ara oni kaluko ju ara won lo.

Eje ki a*oro lori awon omo alaje , pupo ninu awon omo alaje ni won ko mo wipe awon ni aje lara ti won fin wa nse nkan totako aje ara won , ti aje ara won kofi wulo fun won.

Awon apere po ti eniyan ma nfi ma omo alaje, iwo ni kio se iwadi ara re kio le ba mo boya omo alaje nie ati awon nkan tiwa ma fi toju aje ara re, toripe eniyan ti oba ni aje lara tiko ba mo iru nkan ti ole fi ma se itoju won tin fin wa nse nkan totako aje ara re, odidandan ki aje ara re fi sile abi ki aje na ma wulo fun, toripe awon aje yen pe oririsirisi,gbogbo won na ni won ni nkan ti won fe ati nkan tiwon kofe toye ki eniyan to fe ri aje ara re lo koma.

AWON APERE TI OMO ALAJE FIMA NDA ARA RE MA.

ti oba se akiesi wipe owo re mejeji ma nhun e apere wipe omo alaje nio ni.

Tio oba duro si idi oja elomiran tii osi un ta dada, sugbon ti iwo ba duro si idi oja ti ee koni si oja.

Tiwon bagbe oja le omo alaje lori , ko nipe ti won afi ta oja na tan, ama awon iseda kan wa ninu won ti Won kogbodo gbe eru le won lori.

Ti omo alaje bajoko ti eniyan tin ta oja abi otie joko ti eniyan ni shop wari wipe ojare yio bere si ni ta ni kiakia wa si ma ri orisirisi awon eniyan ti won ma wa ra oja ni owo re.

Lara awon apere ti omo alaje fin ma nma wipe ohun ni aje lara, tio ba se akiesi wipe ori amin kan ni omo ka re nibi ila owo alafia re ila yi yio dudu gan.

Business ma nwu awon omo alaje yi se toripe opolopo ore wa ni ibe fun won.

Olohun ma nfi awon omo alaje yi lokan bale laiye toripe kosi nkan ti won ba da owo le tiko ni yorisi rere, afi eniyan ti ogun aiye ba nda lamu ninu won nikan lokun abi eyi tin ba se nkan totako irawo re ati akosejaiye re.

Awon eniyan ma nferan awon omo alaje yi gan nitori aje towa lara won, awon eniyan ma nfe ki won ma joko ti awon ni shop abi ki won ma ba awon ta oja fun awon eniyan.

DIE LARA IDOJUKO ATI ISORO TI AWON OMO ALAJE MA NDOJUKO.

Awon omo alaje ma ni idojuko topo especially idojuko awon agbalagba ki won mo lo ise agbalagba dada kin won leba ri aje ara won lo.

Ogun idile na situn ma nda won lamu ki awon iru awon omo bayin mase gbe family house toripe ati ibe ni ogun tin ma nwo inu aiye won.

Ogun awon ota na situn ma npo fun won especially orogun owo, awon eniyan ma ngbe ogun dide si won ni enu ise won.

Idojuko ile oko(marital problem) na situn ma po fun won toripe won ma ni ife oko won, besini awon kin je kankan ni oju oko won besini oko ama yan won je pupo, awon omo alaje yi si korira lati ma ka ile oko kiri, won je eda toni ifarada won kin fe ki awon eniyan ma ma nkan tin ba nlo ninu Igbeyawo won.

Opolopo awon omo alaje yi okin ri aje ara won latara wipe won koma nipa ara won, iru omo ti awon je , ti won fin se nkan totako irawo ati akosejaiye won , aje ara elomiran ti fi sile lara wipe ohunje eewo irawo ati akosejaiye re.

Awon alagbara ika ti gba aje ara elomiran ni ofin se whala ki otori owo .

Sina sise ni elomira fi le aje ara re kuro, besini afowofa ohun ti owo mi koto ma fi gogo fa ni elomiran fi le aje ara re kuro.

Ba wo wa ni wa se mo iru ogun tin ja iwo ti o ko fi ri aje ara re lo, iwadi ni wase ibeni wati mo iru ogun tin ja o ati ona abayo si iru ogun na , ti wa fi ri aje arare lo.

Aoni wa aiye lasan gbogbo wa ni ama ri aje ara wa lo ni ase eledumare.

Osepataki fun gbogbo eniyan lati mo nipa ara re kio leba mo biwa se rin irin ajo aiyere kio maba wa aiye lasan.

FUN IWADI LORI IRAWO ATI AKOSEJAYE MESSAGE ME PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

AWON IRAWO NI ANPE IRAWO AJE  PART TWO IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️ awon irawo yi je iseda aje ,planet πŸŒ” ti o joba irawo ...
29/08/2026

AWON IRAWO NI ANPE IRAWO AJE PART TWO

IRAWO ERUPE FUNFUN VIRGO ♍️

awon irawo yi je iseda aje ,planet πŸŒ” ti o joba irawo won ni mercury, awon ti abi ni abe irawo yi ni asiri aje lara,koye ki won ma se wahala ki won to ma ri owo toripe irawo aje ni irawo won.

Pupo ninu awon onirawo yi ma je eewo irawo won ni eyi ti o ye ki won ji na si, aje ara awon onirawo yi mi ti fi won si le toripe won fun iseda won ni eewo je, ki awon onirawo yi ji na si sina, sina sise tako irawo won eyi ti o ba nse sina ninu won ogo won yi o ma jo ajo reyin.

Pupo ninu awon onirawo yi ni aje ara won ti fi won sile latara sina sise ati iwa igberaga, pupo ninu won ni won ti se igberaga si awon ti o ye ki won se anu fun won ki won sora fun igberaga.

Ojise ni awon onirawo yi je fun gbogbo awon eniyan papajulo fun ara won, olohun fun won ni emi ifura pupo besi tun ni olohun fun won ni isipaya okan (spiritual).

Awon agbalagba ma ndamu won pupo, won situn ma nda irin ajo aiye won ru, ki awon irawo yi ma gbe family house 🏚 toripe ogun ma gba ibeyen wole siwon lara.

igberaga po fun opolopo won, won ma njo ara won loju pupo, elomiran okin mase loju won ayafi nkan ti won base,

Onirawo yi tio bafe ri ogo re lo ki o sora fun iwa igberaga, sina sise, iwa ijora eniloju, afowofa, toripe afowofa won ma nda irin ajo aiye won ru.

Awon irawo mejeji yi gba amojuto dada lati aro aiye won, ki won malo nkan isora ati nkan awon agbalagba lati kekere won, ositun dara fun awon onirawo yi ki won ma gbe family house 🏚 toripe pupo ninu ogun ti nma ja won ogun idile ni, ki awon onirawo yi na situn jina si awon eewo irawo won ati ikan ti o tako kadara won toripe awon nkan yi na ma nfa ki eniyan ma ri ogo ara won lo.
ONA WONI AJE MA NGBA KURO NI ARA ENIYAN

ki eniyan ma je eewo irawo re abi ki o ma se nkan tio tako kadara re, bi ki won ma wo a*o tikoba irawo won mu, abi ki won ma je nkan ti ko ba irawo won mu.

bi onirawo yi ba feran sina sise ju ti oju re ko kogbe Ibikan, aje ama kuro ni ara eniyan be ni atara ibalopo, melo melo eniyan ni ko mope sina ti ohun se kiri ni ohun fiba ile aiye ara re je toripe ona tio yara ju lati ba aje ara eniyan je ni ibalopo wa.

Eniyan ti ogun awon agbalagba ba nja abi ogun idile ni oti nba iwo ja, iru enibe yio le fun lati tete ri ona lo laiye tabi kio ri aje arare lo eniyan ti ogun awon agbalagba ba nba ja tiko ba tete mura si oro aiye re , osese kio ma ri aje arare lo, ninu ki won baje ma iru eniyan be lara tabi ki won si gba kuro ni owo re .

Ti won ba yo elomiran kuro ninu egbe osese ki aje arare kuro ni arare, kise gbogbo omo elegbe nani ale yokuro ninu egbe awon egbe miran wa to jepe won ni agbara debi pe ti won ba yo omo elegbe kan kuro ninu egbe won ati awon ti won yo omo kuro ninu egbe ati omo ti won yo kuro ninu egbe ni awon egbe omo yen ni won jo ma fi iyaje Won, afi ti won ba se etutu fun won loku.

Awon egbe miran wa to jepe won wa lati maran omo egbe won lowo laiye ni, ama ti won ba yo iru omo ba yen kuro ninu egbe , bi gbape won da irin ajo aiye omo yen ru ni, toripe awon egbe re tio ye ki won ma ranlowo ni won ti le jina si omo yen, eyin tie baje omo elegbe egbiyanju lati ma toju awon egbe yin dada ki won leba ma ran yin lowo.

Awon irawo kan wa to jepe wonko gbodo ma we ose dudu bi won ba nwe ose odudu , nkan ama da ru funwon ni, biki aje ti o wa ni ara won masise ma, oma ndara ki omo elegbe mafi ose white po ise tio fe we.
Osepata fun o lati mo nipa irawo re toripe itosona ni irawo je fun o lati le tete de ibi ogore.

Osepataki fun gbogno eniyan lati lo mo nipa irawore kio le ba ma bi wa se rin irin ajo aiyere

Gbogbo irawo kokan ni won ni eewo ti won, tio ye ki won jina si bena situn ni nkan tio ye ki won mase ti won fi tete de bi ogo won.

FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

IRANSE AJE ATI AWON AMI TI ENIYAN MA NFIN DAWON MO. PART 2Ninu nkan to buru ni ki eniyan ma mo nipa ara re toripe eniyan...
29/08/2026

IRANSE AJE ATI AWON AMI TI ENIYAN MA NFIN DAWON MO. PART 2

Ninu nkan to buru ni ki eniyan ma mo nipa ara re toripe eniyan tiko bamo nipa arare kole mo bi yio se rin irin ajo aiye re .

Oye ki gbogbo wa lo mo nipa iru iseda ti aje , toripe gbogbo eniyan loni nkan ti iseda oni kaluku fe ati nkan tiko fe, ti eniyan bati wa nse nkan ti iseda re kofe odidandan ki nkan ma daru fun iru eniyan be toripe oti fun iseda re ni eewo je niye.

Lomo nipa arare kio leba tete ri ona lo.

IRANSE AJE NI AFE SORO LELORI LONI.

Ninu iranse aje ni ati rii awon egbe bayi.

OSUN AJE

IRANSE OKUN

IGI AJE

EJE KI ASORO DIE LORI IRANSE AJE.

iru awon iseda bayi iranse olohun ni won je, toripe olohun ma nran won wasi ile aiye lati wase omo araye lore ni .

Iru awon iseda bayi ni won nma ya idile ti won o kin se olowo lati wa so won di olowo ati olola.

Iru awon iseda bayi won kin soro Damon toripe aje ara won ko pamo rara, kosi inu ile ti won ba wo odidandan ki aje won inu ile na.

Awon iseda bayi ti won ba se awari ara won dada ti won si toju aje ara won dada, aiye ma rorun funwon pupo toripe aje arawon nilo itoju.

Tio ba to asiko ti awon iseda bayi ma lo aje arawon, won ma la ala wipe awon ri owo eyo ni gbogbo igba ni oju orun won abi ki won ma la ala wipe awon wo a*o fun ti won to owo ayo si lara.

Ikilo ni eyiyi je fun won wipe ki won lose iwadi nipa arawon dada, toripe asiko ti won lo aje ara won ti sunmo.

Nkan tokoba irin ajo aiye elomiran ni wipe aini akiesi lori oro aiye re.

Elomiran wa toje wipe olohun ti fulara wipe asiko ti wa lo aje arare ti sunmo , amo elomiran latara wipe kika nkan kun ni oro aiye re fi daru.

Elomiran aini akiesi lori awon ala tin la ni asiko orire re fi bo mo lowo.

Aje yio fi ile emi atie se ibugbe ni ase eledumare.

asiri po ni abe iranse aje ti akolesotan iwoni kio se iwadi nipa arare kio leba mo iru iseda ti oje ati awon nkan toroma iseda re, kio ma ba damu pupo laiye, kio leba tete ri ona lo ninu irin ajo aiye.

FUN IWADI LORI IRAWO ATI AKOSEJAYE RE MESSAGE LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE.

IRAWO OMI TIKIRU (PISCES) PART ONE1 (FEBRUARY 19 - MARCH 20)Awon oni irawoyi je alagbara, 75% won je omo elegbe omi, pla...
29/08/2026

IRAWO OMI TIKIRU (PISCES) PART ONE1
(FEBRUARY 19 - MARCH 20)

Awon oni irawoyi je alagbara, 75% won je omo elegbe omi, planet to njoba Irawo yi ni (Neptune) irawo ti olohun fun ni imo ati asiri nkan topamo, olohun fun awon oni irawo yi ni ebun (gift) ala lila tori gbogbo nkan ti yio ba sele si won ni rere tabi labiru ni oju orun ni olohun yio ti fi han won loju orun, olohun fun won ni emi ifura ati ebu iriran.

Iwoti oba kin lala tabi o kin riran ninu iwo omo Pisces ♓️ lose iwadi arare otin nse nkan eewo irawo re ati nkan totako kadara re toripe ti eniyan ba nse nkan totako irawo tabi kadara re yio maa di agbara irawo won kuni.

Eleyinju anu ni awon oni irawo yi je won feran lati ma se anu pupo,won situn ma ran awon eniyan lowo, sungbon awon tiwon ba nse loore won saba ma nfi ibi su won ni, alaje eniyan ni won je ninu irawo yi ni awon omo iseda olokun tin saba ma njade toripe irawo yi ni ama si olokun.

Egun idile ati ogun idile ma nsaba dawon la mu, ogun ota ma npo fun won ni eyi toma nse okunfa airi aje ara won lo,ki awon Oni irawo yi mu ojuto oro aiye won dada nipa adura ati sara kiwon situn loma nipa awon asiri topamo si Abe irawo won ati akosejaiye won ki won leba tete ri aje ara won lo.

Awon oni irawo yi ma nni isoro ile oko pupo ninu won ni won kin ri ile oko gbe bena sini awon okunrin inu won okin tete ri iyawo fe, kiwon sora lati ma so asiri won fun awon eniyan toripe won je eda ti nma ni ota gan ota asi ma mu won nibi oro enu won, toripe pupo ninu awon ore won ama je ota siwon,ti awon kosi ni ma afi kiwon sora gidigan.

Won je ologbon, oloye eda, olorire eniyan won, won je eda ti kin tete binu amo ibinu won ma nba nkan je,ki won sora fun ibinu ki ibinu mase le ore jina siwon.

Awon oni irawo yi ma ni idojuko awon eleye leyi tojepe kin je kiwon ri agbara ati ebun ti olohun fun lo,afi eyi ti oba mu ojuto arare dada ni yio tete ri ona abayo si oro aiye re.

Irawo yi ko gbodo ma wu iwa ese(sins) abi kio ma se nkan okunkun(evil things),kosi dara kiwon ma lo a*o dudu toripe otako irawo ati kadara won, Yio ma di agbara iriran (vision) ti olohun funwon ku, yio situn ma fa alakala funwon , eyiyi asitun ma fun awon ota ni opportunity lati ri aburu se funwon.

imole ni awon irawo yi je eni olohun situn niwon, pupo ninu won ni olohun ma lo lati fise ise iyanu.

Won je eda toma nfi asiri won pamo tori won okin fe ki eniyan ri asiri won, won si feran oge sise (fashion ) tori gbajumo eniyan niwon je.

Awon onirawo yi ogbon ori won biti ijapa ni toripe won ma nfi ogbon pa iro ti eniyan yio si ro boya oto ni won nso.

ninu awon ise todara fun awon oni irawo yi ju ni ise iranse fun eniyan tia bafun ni ebun iriran ninu won, toripe awon gangan ni iranse olohun.

Awon oni irawo yi ma ndi atunbi ni igba tiwon bati pe omo 40 years laiye, fun awon ti won ba jina si awon iwa ibaje ati iwa ese, ati awon tiwon ba rin ilana ise iranse ninu won, ti olohun yio si mafi orisirisi nkan han won, ni awon nkan ti opamo toje bi asiri , iriran won yio watun ju ti tele lo.

Awon oni irawo yi ma ni isoro omo bibi pupo, ninu won lati mari obinrin ti yio mafi operation bi omo ni opolopo igba, opolopo oninrin won okin ni anfani lati bi omo pupo laiye.

AWON EGBE INU IRAWO YI

Omo omi lopoju ninu irawo yi

Omo omi olokun aje
Iranse omi
Iranse aje
Omo omi oluweri
Igi aje

Awon egbe yi ma saba jade ninu irawo omi Pisces, wonsi tun le jade ninu irawo miran sugbon kowopo, omo alaje lopoju ninu awon omo Pisces ♓️ sugbon oma nira ki opolopo won tori aje nalo.
Oko ti oba fe awon oni irawo yi aje ara won ma nran ti oko won lowo, leyi tojepe nkan yio ma lodede funwon ti oko sini rahun owo rara, amo nkan ti oma nfa akoba fun awon oko won ni wipe won okin ma iru iyawo ti awon gbe si ile.

Asiri po ni abe irawo yi ti akole sotan iwoni ni kio se iwadi arare kio le ba mo iru eniyan tio je ati bi wa se rin irin ajo aiye re tiwa fi tete ri aje arare lo.

FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE....MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA LORI PROFILE MI.

Address

Ilorin
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Aworawo pelu itumo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share