22/12/2025
ASIRI EBU OSHOLE OWO TA FIN GBE NKAN RERE SE LAYE TABI LATI DI OLOWO ATI OLOLA NI ODE AYE TO YARA GBERA NI KIAKIAISE NARE 👇
Ako Alangba kan totobi dada die
Abo alangba kan totobi dada die
Ewe Ojukoro merindilogun (16) oojo
Ege Eran elede tutu die
Owu dudu ati owu funfun
Ewe Ola topo dada die
Odindi Atare kan
Otin Schnapps Cup kekere kan
SISE RE 👇
A la aya ako alangba
A o la aya Abo alangba
A o wa ko gbogbo ifun inu ako alangba kuro
A o tun ko gbogbo ifun inu abo alangba na kuro A o wa ko awon ifun mejeeji sinu ara won (ifun ako alangba sinu abo alangba, ifun abo alangba sinu ako alangba)
A o wa ko ewe Oju oro mesan sinu Abo
A o ko ewe Oju oro meje sinu ako
Eran elede kekeke mesan sinu abo
Eran elede kekeke meje sinu ako
A o wa ran mejeeji pa lotooto pelu
owu dudu ati funfun A o wa si aya awon mejeeji derawon
A o fi #1,000 Tuntun we awon mejeeji papo A o gbe sinu ape ijonkan A o fi odindi atare nla kan si legbe A o wa ko ewe ola bo lori mole
A o jo papo, a o lo kunna daadaa
LILO RE 👇
Ago kan oru (1 am) ni a o lo gbogbo ebu na pelu otin schnapps A o se adura owo si daadaa ki a to lo ebu na.
+2348176778076