Ifa olowo isese lagba

Ifa olowo isese lagba Dis page is blessing fo

18/02/2026

tested and confirm

27/08/2025
15/08/2025

Oshole todaju

15/08/2025

Hope you are still with me eku ọjọ mẹta ooo

13/09/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Adepeju Akintola Bakare, Joseph Huyyi

06/09/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Timothy Arowolo Olarinde, Popoola Emmanuel

23/07/2024

Shout out to my newest followers! Excited to have you onboard! Omo Ajeh Ifadollar, Alfa Arowosaiye you are welcome

Atunde to daju oba oninu re ao ao wa πŸ… to pon dada to le dada ao ge si meta ao mu ti arin re ao fi si ori kaikai ao bu i...
18/06/2023

Atunde to daju oba oninu re ao ao wa πŸ… to pon dada to le dada ao ge si meta ao mu ti arin re ao fi si ori kaikai ao bu iyo die si ao lo fi we lati ori dele aro tabi ale loda ju odaju gan iba re ifa la

Iku haaa koba ma je o wun haaa iku ma yawo pami tomotomo tayataya tebitebi pelu awon ololufe mi sun re ooo eledumare a f...
15/05/2023

Iku haaa koba ma je o wun haaa iku ma yawo pami tomotomo tayataya tebitebi pelu awon ololufe mi sun re ooo eledumare a fi orun ke πŸ™πŸ™πŸ™

15/05/2023

Imole aje

26/12/2022

Atude owokowo

EKU asin tutu
egbo tude
eso owerenjeje
odidi atare kan
ao yin gbogbo omo inu re sinu igo ao fi tele inu igo
ao ko eso werejeje si lori eku asin yoo tele egbo tude yoo tele

ao wa fi a*o pupa si lori,

akieyesi lori egbo tude yio tutu toojo ni o gbodo je ooo

ojo ti abase ise yi na ni ao da omi alale gidi too yayi si lori ooo yoo bawa lara mu ooo amin,

lilo re
o ni agbara die o a le malo idaji gasi kekere na toba ti wa wora dada ale malo kikun re

Address

Asiriabo Isolo Number 1
Isolo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ifa olowo isese lagba posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Ifa olowo isese lagba:

Share

Category