Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

  • Home
  • Nigeria
  • Oke Ogun
  • Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere MOSHEYBOLATAN SPIRITUAL AND NATURAL HERBS REMINDER 💊DOCTOR HERBAL SPIRITUAL MEDICINE MOTIVATIONAL

  OLOGO FIMA NRI WAHALA ATI IDAMU NINU AIYEOpolopo eniyan lonjiya ogo sugbon wonkoma okufa re, wahala ati idamu po ninu ...
30/06/2026

OLOGO FIMA NRI WAHALA ATI IDAMU NINU AIYE

Opolopo eniyan lonjiya ogo sugbon wonkoma okufa re, wahala ati idamu po ninu irin ajo aiye elomiran tikoma ona abayo si, awon Agba ama da elomiran laamu tiwon konije koni ilosiwaju ati aseyori Lori gbogbo nkan toba dawole...

Awon ota ama de awon agba si elomiran tiwon omabaja, eleyi ni koni je kio ni aseyori lori gbogbo nkan toba dawo le...

Omo ologo tobafe jade ninu idile Miran bayi, awon agba tiwon bawa ninu ile yen mapa owopo gbe ogun ti awon tiwon febi iru omo yen latimari omo yen bi... Ase olohun ni iru awon omo yen fima nwasi aiye, anu olohun ati igbinyanju ni won fi ma nri aiye gbe...

Atigbati won tibi elomiran ni aiye tigba ogo re pamo..

AWON WONI ANPE NI OTA (ENEMIES)

Ota Pe Orisirisi...

ONI WAHALA

elomiran okan ma ba eja lasan laise ogun sie,wahala nikan nio ma baefa, koni nkan kan Miran tofe se ju koma baeja lo.. enu lasan ni iru awon ota yi ni.. Ija nikan ni won oma ba eja..kosi si nkan tiwon kole ba eja lelori..



ALABOSI

Elomiran oma dina ore ma e, gbogbo awon toye kiwon sanu re ni yio ti ro ejore laburu funwon lati kodi ore yen, gbogbo ibi ti oye kioti ni iyi ati aponle niwon otima ba eje.. Alabosi waninu ota

OTA TO LAGBARA JU NI ENIYAN TO SE ASASI SIE

Awon eniyan yi burugan debi pe oni mape ota niwon je sie, koda won otun mase dada sie, wonle je ore(friend) sie, alabagbe,oga lenu Ise, egbon tabi aburo tabi iyawo tabi oko, tabi ninu ebi (family)...

Awon ota yi niwon ma nse ogun tolagbara si eniyan latima ri ilosiwaju ati aseyori ninu aiye, iru won ni won ma ran awon agba si eniyan lati ba eyan ja, wonle fi amin ikorira si elomiran lara, wonle male ore jina si eyan... Kosi ona tiwon kole gbawole si eyan lara latari ogun tiwon oma sesi eyan..

Awon agba lewa ninu ota ti eyan ni, fun awon toba ni ogun idile tabi awon agba nba onitohun ja...

Asiri po labe topic yi timio lema so... iwo ni kiose iwadi lori oro aiye re kole mo ona abayo si isoro aiye re...

FUN IWADI LORI IRAWO RE TABI AKOSEJAIYE, SPIRITUAL CONSULTATION... MESSAGE ME PRIVATELY ON WHATSAPP NUMBER 09026696046 OR CALL ME 08032499603

 (HATRED)_ATI_ONA_TI_OMA_NGBA_WONU_AIYE_EDA🌟 Ami ikorira je ami buruku to ni agbara pupo.• O si lewu pupo fun isemi eniy...
28/06/2026

(HATRED)_ATI_ONA_TI_OMA_NGBA_WONU_AIYE_EDA

🌟 Ami ikorira je ami buruku to ni agbara pupo.

• O si lewu pupo fun isemi eniyan ti asasi yi ba n da lamu.

• Orisirisi nkan buruku ati bad luck ni o ma n sele si iru eniyan bee.

• Eniyan to ye ki o se eyan lanu, yio si ma korira enina latara ami buruku yi.

• Awon eniyan o kan dede ma binu si i lainidi kan pataki.

• Eleyi ki je ki anu o wole fun eniyan.

• Ko si ibiti irufe eniyan bayi le de laiye ti awon eniyan mafi ife han si i afi ki won ma binu si i.

• Ko si iru aburu ti ami yi ko le fa sinu aiye eda.

• Ami ikorira ma n mu ifaseyin wonu aiye elomiran.

• Lati igba ti ami buruku yi ba ti wa lara elomi, ni ko tini si ilosiwaju ninu ise re mo.

• Irufe eniyan bayi yio wa di eniyan ti ko ma se ma larin awon akegbe re.

• Eniyan to ti wa ni ipo giga ninu ise re tele.

• Won dede bere si ni korira re debi ti won fi ma yo kuro ni ipo asiwaju to wa.

• Asewaju re wa konidi ero eyin oo... ase.

• Ami ikorira lo fa ti elomiran fi n ri ijakule pelu ololufe re.

• Gbogbo igba ti won ba ti ni ibalopo ni yio bere si ni korira re t**i ti yio fi so pe ohun ko se mo.

• Elomiran wa tosepe ami ikorira yi ni koje koni oko tabi aya..

• Ona ti ami ikorira ma n gba sise aburu lara eniyan po ti ko se so tan.

• Iwo ni ki o se iwadi nipa irin ajo aiye re ki o le mo iru isoro (spiritual problems) to n da o lamu ninu aiye re.

ONA TI AMI IKORIRA MA NGBA WONU AIYE EDA

• Orisirisi ona ni ami ikorira yi ma n gba wonu aiye eda.

• Sugbon ma so die ninu re.

1. ASASI (SPIRITUAL ATTACK)

• Asasi aiye lo di ami ikorira si ara elomiran latara ogun idile tabi ogun aiye to n da lamu.

• Elomiran ti wa ninu ide awon eleye lati ojo ti o ti pe.

• Ninu awon aburu ti asasi aiye ma n fa sinu ara eniyan ni ami ikorira wa.

• Elomiran wa n se wahala lati tesiwaju ninu aiye.

• Sugbon asasi yi ko je ki igbinyanju re oni ipa gidi.

😢

2. EWO IRAWO ATI KADARA (FORBIDDEN THINGS)

• Aimakan ni elomiran fi n ko ba ara re latari pe ko mo awon ofin ati ilana ti irawo nfe.

• Gbogbo irawo lo ni nkan ewo tie.

• Beeni gbogbo iseda eniyan lo ni awon nkan to tako kadara re ti ko gbodo se.

• Eniyan to ba n se awon nkan ewo irawo ati kadara re.

• Ninu awon aburu ti o ma sele si ni ami ikorira wa.

NOTICE 👇

Awon ipenija lorisirisi ti eda eniyan lema koju, tosi lefa aini ilosiwaju ninu aiye eda.

Lotito nipe igbinyanju ni eda ngba, tolohun lomase.... sugbon sibe na igbinyanju yi na loma satokun kadara.

Tioba dake si oro aiye re, tarare yio bo dake, gbe igbese loni lati ri ona abayo si isoro aiye re.
.........
GBOGBO IRAWO LONI ADAMA ATI ISESI TIWON....
EWO(FORBIDDEN) ATI AWON NKAN TOBA KADARA ONIKALUKU MU...
FUN IWO TIO BAFE MO NIPA ISEDA IRAWO ATI KADARA RE...
MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA 09026696046/08032499603 FUN IWADI (CONSULTATION) NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE...

Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere
if you find this interesting, kindly click the link on my bio to join our WhatsApp group audio program.

👍Like, comment, follow, and share....

 Bose baami share message yi fun opo eniyan lagbara Olohun wadi ogo apesin Amin 🙏 🤲 🙏 Opa aje je asiri aje ti olohun ma ...
24/06/2026



Bose baami share message yi fun opo eniyan lagbara Olohun wadi ogo apesin Amin 🙏 🤲 🙏

Opa aje je asiri aje ti olohun ma fi si ara eniyan ti obawu, eniyan ti oba ni opa aje yi ni ara ile aiye re ma ro run yio ma ri ti aje se, koni na owo kan tan kio to ri owo miran, eniyan ti oba tun fe won si ile, aje ara won yio ma ran ti ololufe won lowo lopin igba ti oloufe won batin nse dada siwon.!!!

Opa aje ma nwa ni ara obinrin bena sini oma wa ni ara okunrin amo ara awon obinrin ni oma wa pupo ju.!!!

Opa aje yi man sa ba wa ni ara awon omo elegbe!!!
Iwoti oba je omo elegbe lose iwadi nipa arare kio le ba mo iru aje tin be ni ara tie toripe awon aje pe orisirisi gbogbo won si ni won ni eewo ti won, iwo ti o ba mo ipe oni aje ti owa nse nkan tio tako aje ara re Odidandan ki aje arare fio sile lo.!!!

Oko ti oba fe awon obinrin tio ni opa aje ni ara ni opin igba ti oba tin se dada si tio sin mu inu re dun aje ara re yio ma sise fun.!!!

Iru awon omo yi ti won ba ti se awari ara won tiwon simape awon ni opa aje lara, won kin gba ki okunrin miran bawon ni ibalopo afi oko won nikan toripe won mape okunrin ti oba nbawon ni ajosepo, aje ara awon yio ma sise fun eniyen.!!!

Opa aje ma nwa ni owo ati ese, iru awon omo bayi ko si inu ile ti won ba wo ti aje ara won ko ni ma sise nibe koda ti won ba gbe owo le oja tiwon se adura pe aje ma wa pelu ase olohun won ma wa ra oja na ni kiakia afi tiwon ba ti gba opa aje arare nikan loku.!!!

Oko ti oba fe awon obinrin yi gbodo ma toju won dada.!!!
Won ko gbogbo fi iya je won o, ojoti won ba ti bere sini se nkan ti obiwon ninu tiwon sin nfi iya jewon ojona ni aje ara won ko ni sise fun okunrin yen ma toripe nibi kio ma mu inu won dun ni aje ara won yio ma fi sise fun o.!!!

awon iseda yi gbodo sora fun ija abi epe koda ibi ti won ba tin ja ,tiwon sin se epe kiwon jina sibe toripe eewo ni oje fun aje ara won, won ko gbodo jan ese male tabi kiwon pa atewo se epe le eniyan ni igba tiwon ba nja kodara fun won eewo loje fun iseda won.!!!

Ki won ma wo a*odudu, a*o funfun ni odara fun ju lati ma won.!!!
Ti won ba nwo a*o dudu tabi a*o pupa aisan ati ikorira ni yio ma sele siwon , osi tun le de na riri owo won.!!!

Aje olokun a*oro dayo wafi ile mi se ibujoko wafi odede mi se ibugbe.!!!

Aje yio fi ile wa se ibujoko ni ase eledumare.!!!

GBOGBO IRAWO LONI ADAMA ATI ISESI TIWON....
EWO(FORBIDDEN) ATI AWON NKAN TOBA KADARA ONIKALUKU MU...
FUN IWO TIO BAFE MO NIPA ISEDA IRAWO ATI KADARA RE...
MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA 09026696046/08032499603 FUN IWADI (CONSULTATION) NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE...
Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere
Fun Iwo tonfi igbagbo ninu Olohun re se Amin adua yi lagbara Olohun wadi ogo apesin 🙏🤲🙏

🗣 IWURE OJO AJE 💰Bò ti le wu ki ose yi ri 🫵Aje oni je ko mo iyaaa 🫵Aje oni je ko mo oosi laye re 🫵Ose yi oni le mo e 🫵 g...
22/06/2026

🗣 IWURE OJO AJE 💰

Bò ti le wu ki ose yi ri 🫵
Aje oni je ko mo iyaaa 🫵
Aje oni je ko mo oosi laye re 🫵
Ose yi oni le mo e 🫵 gbogbo ohun
to je inira 😭oni ba won ri 🫵 Aje oni pe e
ran ni ise 🏃‍♂️🏃🏽‍♀️ bo ti le wu kori lo ose yi 🫵
Aje oni fi ebi paa e 🫵 Iwo gangan ni wa ran
Aje ni ise 💸💵💶💴 Owo nla-nla ko ma nbo
lodo re 🫵 Aje ko yaaa odède re waa loni oo💰

Wa ni Owo lowo 🤲 wa ni Aje ni ile 🏠
Wa fi Aje ba wón se gbogbo ohun rere
ti wón fi Owo 💸💵💶💴💰da ni ara 🫵
Ose yi ma gbe gbogbo waa si rere ooo 🤲

Ase Edumare 💰🕊👏
Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

21/06/2026

ÀLÀYE NÍPA ALA ATI ITUMORE ATI SAARA RE.

Olorun ara gbgb wa lowo alabuku oni se lori eni kankan wa e ma bawa shere fun afani elomiran kii awa na legba lada lati bee adura gbgb wa agba lagbara olorun 🙏 🤲 amin 💖

(1) APATA. (Mountain 🗻) :- Ti eniyan ba la Ala
pe ohun wa lori Apata giga kan ti odo Ogede wa po nibe ti won supo si oju kan na ohun wa nwo awon kan ni sale.

Itumo re: Olohun yio se eni na ni eniyan giga ni aiye agbara ota ko ni ka o, wa situn ju awon egbere lo.

SARA RE

Eo lo wa eyikeyi ninu nkan oko ni yio fi se sara fun awon eranko , bi Agbado, Okababa , Ewa, Iresi, pelu aniyan wipe ki itumo Ala re koribe.

(2) A*O EKISA (rags) :- Ti eniyan ba la Ala pe ohun wo a*o Ekisa

Itumo re: Eni na Olohun yio se ni eni Aponle ti awon eniyan yio ma sa si abe iboji re lojo iwaju sugbo oni lati mura oo.

SARA RE

iru eniyan be yio wa nkan eyo tutu, se sara fun arugbo Obinrin bi raisi, agbado, okababa tabi Ewa pelu aniyan ala yi ki olohun jeki oribe.

(3) A*O TUNTUN (new cloth 👕 :- Ti eniyan ba la Ala pe ohun wo a*o Tuntun.

Itumo re: Eni na iyi re yio dinku, mimo jade re yio si dinku laise ti aisan.

SARA RE

Eni na yio dana Amola yio se obe eja abori si bi oba se ni agbara mo awon agbalagba ni yio je pelu aniyan ala re.

(4) ALFA (cleric) :- Ti eniyan ba la Ala pe ohun ri awon eni Olohun tabi awon Alfa oni mimo.

Itumo re: Eni na yio ri Agbega iyi ti yio dun mo ni bi ise re tabi ati lori gbogbo nkan ti oba dawole.

SARA RE

Eni na yio wa orisi nkan eyo se sara Agbado, oka, Iresi, yio da aniyan si, yio fise sara fun afoju okunrin, to ba we lawani.

(5) ATA PUPO:- Ti eniyan ba la Ala ri ata pupa to pon wee.

Itumo re: Iru ala bayi otumo si Iponju fun eni na.

SARA RE

Eni na yio be awon eni olorun kii won ba o wu pa eran oruko yio fi se sara ni tutu pelu aniyan pe ki Olohun so ohun nibi Iponju.

(6) AGBO ILE NLA( big family compound ) :- Ti eniyan ba la Ala pe ohun wa ni agbo ile nla kan.

Itumo re: Eni na yio je jagunjagun ni agbo ile nla kan ti eni keni ko nile fi owo pa idare loju ti a ma da abo bo awon to wa ni agbo ile na.

SARA RE

Eni na yio ro Oka Amola pelu obe eran Ogunfe se sara pelu aniyan, ki wa se dandan ni ko pa odidl eran o, kio se bio base ni agbara mo.

(7) AFARA ODO( bridge 🌉) :- Ti eniyan ba la Ala pe ohun koja lori Afara omi.

Itumo re: Eni na yio ni aseyori ti yio ni ifokanbale ti koni si ijaya fun.

SARA RE

Eni na yio ra Akara elepo 41 yio fi se sara fun omode ati agba, Okunrin ati Obinrin.

(8) AFARA ODO(?bridge 🌉 ) :- Ti eniyan ba la Ala pe awon meji pade lori Afara omi ewa jo nsoro enikan wa pada si eyin koto ori afara na mo, enikeji si to ori afara na ja.

Itumo re: Eni to pada lori afara ni oni'diwo ota, ota to sun moni.

SARA RE

Eni na yio ra bata tuntun iru bata ti oba ni lagbara latí ra yio fi se sara fun Okunrin to je Alfa pelu aniyan isegun ota.

(9) ENIKEJI:- To gun ori afara yio se sara owo naira marun, meje fun Okunrin merin afoju Obinrin meta.

(10) AJA:- Ti eniyan ba la Ala pe Aja bu ohunje tabi ofa ohun lewu.

Itumo re: Eni na yio ri ija awon agbalagba, ti oba pa Aja na isegun ota ni .

(11) ATO (s***m ) :- Ti eniyan ba la Ala pe Ato jade ni arare ni oju orun.

Itumo re: Ti eni na baje akoda yio ri owo, bukata re yio si biya sugbo tibko base akoda ala ye tunmo si ifaseyin oo...

SARA RE
Eni na yio to awon oni mimo lo lori saarayin yio wa owo naira meje yio fi se sara fun awon omo kekere okunrin ati obinrin pelu aniyan lori ala.

Note: eniyan ti oba la ala wipe ato (s***m) njade ni ara ohun ni oju orun, nigba ti otaji oti ba ato ni gbogbo ara re ala yi kodara won ma fin dena ogo eniyan ositun ma nfa ifaseyin, ati amubo, toripe eniyan ti oba ma nsaba la iru ala bayin awon agbalagba ni won damu re kii o mu ojuto ara re gidigan

GBOGBO IRAWO LONI ADAMA ATI ISESI TIWON....
EWO(FORBIDDEN) ATI AWON NKAN TOBA KADARA ONIKALUKU MU...
FUN IWO TIO BAFE MO NIPA ISEDA IRAWO ATI KADARA RE...
MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA 09026696046/08032499603 FUN IWADI (CONSULTATION) NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE...

Today Is final day of  hijrah 1447Ah June 15th   *prepare for the new year Hijrah 1448AH tomorrow biznillah  welcome the...
15/06/2026

Today Is final day of hijrah 1447Ah June 15th
*prepare for the new year Hijrah 1448AH tomorrow biznillah
welcome the new year Hijrah 1448AH by
* seeking Forgiveness Istighfar
* give Sadaqah charity
* Dhikr and Tahajjud voluntarily
* dua corresponding to 1448
* يا حبيب 22
* يا ملك 90
* يا دايم 55
* يا غفار 1281
* 22+90+55+1281= 1448.
* والذين ءامنوا وهاجروا وجهدوا في السبيل الله والذين ءامنوا ونصروا أولئك هم المؤمنون حقا لهم مغفرة ورزق كريم. سورة الأنفال ءاية 74
* odun ayo lao se Amin
* Al-Kabiry Mosheybolatan Nuruniyas
Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

🤴🏽👸ISEDA OLOKUN👸🫅            💸💸💸💸💸Aje olokun a*oro di ayo, wafi ile wa se ibugbe.... Je ki gbogbo wa  ma  ri aje je? ,sh...
13/06/2026

🤴🏽👸ISEDA OLOKUN👸🫅
💸💸💸💸💸
Aje olokun a*oro di ayo, wafi ile wa se ibugbe.... Je ki gbogbo wa ma ri aje je? ,shey gbogbo wa lala aje?. Amen

Aje yi je nkan tio ma sise owo wafun eda eniyan, ti ogo eniyan sima tete buyo ise keke re owo nla, koda eniyan lema ni ise gidi kan lowo ti owo asima wole ni onakona, eniyan ti aje ba wa ni arare tikosi je ewo aje tabi awon ti ika eda kofi oju si lara debi tiwon madena lati ri aje re lo, iru eniyan be mama ri owo ni ona tiko ro rara... Iru won ni won ma ntete ni owo lowo... Ni owo toje owo nla.

Awon iseda kan wa ti anpe ni olokun, awon eniyan yi ko wopo ninu aiye, besini akin tete dawon ma tori pe bi eniyan yepere lase ma nwo won...
Awon iseda yi ni asiri oro (wealth) lara..
Koda awon elomiran ninu won atunma rin irin emi, leyi tiwon mari opolopo asiri nipa aje (wealth) sugbon wonko gbodo sofun eniyan kankan..
Awon olokun je iseda tolagbara pupo debipe tiwon ba duro ti eniyan to nta oja, yio si mata
Koda tiwon bafile sadura fun eniyan pe aje awa... Won mari oja yen ta lase olohun..

Ase ati Agbara awon iseda olokun wani eyin oju won Ati atele wo mejeji won..
Tori re ni awon oloju inu (magic eyes) fima nri Imole ninu eyin oju won pelu atelewo won..
Gbogbo nkan ti awon iseda yi bafi owo won kan loma ndi rere (fortune)..
Ile aje ni awon iseda yi tiwa besini iseda owo ni adawon...
Ti won ba gbe owo(hand) le eniyan Lori tiwon sise adura fun eniyan, olohun sima gba adura eniyan yen tori ase Ati agbara towa ninu owo yen... Kabiesi eledumare 🙏

Gbogbo igba ni Imole ma nta ni owo won tori eni Imole (light) niwon je...

Ti olohun bafe da idile kan lola... Yio mu iseda olokun wa lati inu idile yen, orire nla loje fun idile toba bi iru omo yen...
Tori omo yen leso gbogbo idile won di olowo pelu ase olohun..
Iseda olokun lale fiwe osa aje (god of wealth)

Iru awon omo iseda olokun yi nilo amoju to gidi lati kekere won tori ki awon aiye magba abode funwon...
Koda awon aje (witch) aiye okin fe kiwon wasi aiye sugbon pelu ase Ati agbara olohun ni won fima biwon si aiye..
Opolopo obinrin tiku toyuntoyun.. Kise tori nkankan, tori omo tofe bisi aiye ni won fipa toyuntoyun...

Obi tobati ma iru omo ti ohun bi koma mojuto..
Koda awon iseda yi kogbodo gbe family house rara tori ki wonleje kiori ogore lo..
Awon omo iseda olokun yi tigbodo kuro ninu ilu tiabiwon si lati omo odun meje si mewa tori won ma ni ogun idile tole gan..

Opolopo eniyan okin da awon iseda yin ma tori ama nfi oju eniyan yepere wowon, asini ma ipa tiwon nko ninu igbese aiye ldile tiwon wa..
Ojo tiwon ba kuro ninu idile yen ni ama toma iwulo won..
Opolopo okunrin ni iseda olokun yi ninu ile gegebi iyawo sugbon koma... ijo ti wonba korawon sile loma toma pe ohun tiso nkan nu...
Iseda olokun yi po ninu awon obinrin dada sugbon okunrin kowopo ninu aseda yi..
Okunrin inu won kosoro dama, tori iwa ati isesi re yio ni mase afihan pe olola eniyan ni..

IRAWO & ABUDA WO NI ANPE NI OLOKUN

Kosi inu irawo ti iseda olokun kosí bẹẹni ninu abuda konkan ti kotile jade sugbon ọ wopo ninu awon abuda yii akosile yii

IRAWO OMI & ABUDA OMI EYO KAN LO NINU OLOKUN

Abuda omi tia npe ni (Pisces).. abuda yi gangan ni anpe ni olokun, awon iseda yi po dada ninu abuda yi..
Tori re ni afi funwon ni agbara emi ati isipaya okan (spiritual powers)
Opolopo won ma n rewa gidigan, iseda aje po ninu won, wonsi je alala (dreamer) ati ojise (prophet)

IRAWO ERUPE & ABUDA ERUPE EYO KAN LO WA NINU OLOKUN

Abuda erupe kan wa tia npe ni (Virgo)
Iseda olokun wa ninu abuda yi dada tori kikida aje ni awon tiabi sinu abuda yi sugbon ogun idile ma npo funwon.. Tori opolopo won okin ri aje arawon lo, ayafi eyi toba je onigbinyanju, aladura pelu Sara lopolopo...
Opolopo won ma nje ewo leyin toma fa ti aje arawon fima nfi wonsile...

IRAWO AFEFE & ABUDA AFEFE EYO KAN LOWO NINU OLOKUN

Abuda afefe kan wa tia npe ni (Gemini)
awon omo olokun ma nwa ninu irawo yi na dada tori iseda aje ni won je..
Abuda yi ni idojuko pupo, koda aiye ma nfe suwon lopolopo igba tori wahala ati idamu yen tipoju fun won..
Ninu awon abuda ti awon agba ma ndalamu ni Gemini wa.... Adura ati Sara lolefi segun isoro re..
Opolopo omo obinrin Gemini tunma ni isoro ibujoko ati oko orun...
Besini awon okunrin won amase sina dada tabi kiwon ma fi iyawo tole..

IRAWO INA & ABUDA INA MEJI LOWO NINU OLOKUN

Iseda olokun yi kowopo ninu abuda Ina rara...
Ayafi die die ninu abuda Ina Aries ati Sagittarius.. Sugbon wonkopo rara...

Abuda Agba ni abuda yi je tori asiwaju ati oludari ni won... Tori re ni won nilo lati malo nkan awon Agba dada.. Kiwon mama ba ise won je...

ADAMO ATI ISESI AWON ISEDA OLOKUN

Awon iseda yi feran lati mawo a*o funfun tabi kiwon malo nkan funfun tori adamo won ni..

Iseda yi koferan kioma je eja odo (eja aro)
Tori Oma nrinwon laya.. Iseda won ko

Iseda yi ko feran sina sise koba iseda won mu.. Sina sise ma ngba agbara lowowon ni

Imole ama saba ma ntan ni oju ati owo won tori eni Imole niwon... Sugbon awon oloju inu loma nri gbogbo awon apere yi larawon..

Ase ati agbara wa funwon Lori gbogbo nkan tiwon bagbe owo le tabi tiwon nro si okan..

Olowo ati oloro ni won ma nje laiye... Tori owo ati ola won koni afiwe, asiri oro won kole yen eniyan kankan yatosi ohun ati olohun oba tose edare...

Etc...

SE IWADI ORO AIYE ARARE KIOLE BO NINU ISORO

FUN IWADI LORI IRAWO RE TABI AKOSEJAIYE, SPIRITUAL CONSULTATION... MESSAGE ME PRIVATELY ON WHATSAPP NUMBER 09026696046 OR CALL ME 08032499603
Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

🕷️🕸️🕷️🕸️ *ALAYE LORI EWÚ ATI AKOBA TI OWA NINU ÒWU ALANTAKUN* 🕸️🕷️🕸️🕸️Kini won ùn pe ni Alantakun🕷️🕸️?Ohun tí oburu ju n...
10/06/2026

🕷️🕸️🕷️🕸️ *ALAYE LORI EWÚ ATI AKOBA TI OWA NINU ÒWU ALANTAKUN* 🕸️🕷️🕸️🕸️

Kini won ùn pe ni Alantakun🕷️🕸️?

Ohun tí oburu ju ninu aiye eda nii kii ama fii ojú kò òwu *ALANTAKUN* 🕸️
Njẹ iwọ mọ wipe bíi ọmọ onile ba pọju ninu ile odidandan kii òwu alantakun 🕸️ máa dá ẹni láàmú.
Ìmọ nipa igbesi aye fiye wa wipe Alantakun je Okan ninu awon Omo iranse esu,(witch and wizards) osi je Ami buruku ninu igbesi aye Omo ènìyàn eyii sije oludena ògo aiye ẹda.

*ÀKÍYÈSÍ*

1. Ti a ba lala ri loju orun kosi bi abase se gbiyanju to walahi pabo ni yio jasi.. kiwan Fi 1 million se Ogun fun yen Ogun kole sise Lara onitoun ayafi Komura gidi gidi gan

2. Ti aba lo si ibikan ti Alantakun bako wa loju wallahi kini Koni bosi. Ti oba bosi wallahi konisise tabi kosonu loju ona..

3. Ti aba losi interview tabi logba nkan lowo eniyan iri Ajo Koni da

4. Gbogbo enikeni ti Alantakun saba maa koloju wallahi atije eniyan eninaa ninu okusi Owo eledumare ayafi Komura gidi gan

5. Ti Oni sowo tabi oloja nbasa Fi ojumo ko Alantakun Komura Ojo naa tabi oja re koniloo dedeede.

6. Bi Omo okunrin man saba Fi oju ko Alantakun Komura Koni Tete ni Iyawo beeni fun obinrin Koni Tete ni ade Ori..

7.Ti abari Alantakun bafo Siwa Lara ni nsaba jaa Ogun arawa beeni insaba maa fe ikori ta fun eniyan..

8. Alantakun ninu Ile ni nma faa ifaseyin , osi, ilekoko, rada rada sinu Ile naaa ti Koni Nini ona Abayo

9. Alantakun ninu shop inma fa okuta si oja beeni gbese fun onisowo

10. Alantakun ni agbara Debi wipe ti awon mama mi no network failure bafe daamu eniyan ni oju orun aofi lala asile bani ni ara eniyan bi ila kaakiri ara.........

Gbiyanju ki o ṣe àwárí ara-re kii omaba waye wáyé asan.

GBOGBO IRAWO LONI ADAMA ATI ISESI TIWON....
EWO(FORBIDDEN) ATI AWON NKAN TOBA KADARA ONIKALUKU MU...
FUN IWO TIO BAFE MO NIPA ISEDA IRAWO ATI KADARA RE...
MESSAGE MI LORI WHATSAPP PELU NUMBER TOWA 09026696046/08032499603 FUN IWADI (CONSULTATION) NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE...
Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere

Address

Iseyin
Oke Ogun

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to Mosheybolatan Imọ ijinle Nipa Aseyori Eda Irowa Eda Itumo Alalila Omo Emere:

Shortcuts

Share