Asiri ewe ati agbara egbo

Asiri ewe ati agbara egbo fun orísirísi iwosan

14/06/2023

Moki gbogbo wa ku ifarada asiko yio, eledumare koni kodi aimonse sí ẹni kọkan wao, ti aba ni ki gbogbo wa wo bi inkan seri lasiko yi ao ri wipe ọpọlọpọ sise ṣiṣe loti n'dabi ole leyi ti osi je ki opo okunrin di alai mo se lodo obinrin míràn, eyi l'omumi lati fẹ yọnda asiri bibo yi, ki oni kaluku wa gbiyanju rẹ wò, ki afi wa bibo asiri kiakia,
Àṣírí náà niyi,
Ao wa eso ta gììrì odidi kan, ti oni àjé lara dáadáa, ao pa ni panṣa, ao ko idoti inu re danu, ao wa ekiri ẹran maalu kan, tí koiti wo omi, koni sise fun ọ ti o bá share rẹ kio sí like page yii, tori anfani elo miran,ao fi ekiri ẹran maalu náà sí inú tàgíìrì náà ao dé pa, ao gbé tàgíìrì náà lé orí iná fún bí ọgbọn isẹju,30 minute, ao wa je ki ọ tutu niwon ba, ao wa yọ ekiri ẹran yen ninu tàgíìrì náà,ao ju senu ni ẹẹkan náà, ao je. Yíó bawa lara mu oo, sope àṣírí témi koni tu ooo.

(1) Efo GBURE ati EGBO RE wa fun ;  OWO TO NGBON, AHAN to nlo. (STROKE) A o tu GBURE pelu egbo re a o foo daradara a o s...
13/06/2023

(1) Efo GBURE ati EGBO RE wa fun ; OWO TO NGBON, AHAN to nlo. (STROKE) A o tu GBURE pelu egbo re a o foo daradara a o se fun iseju marundinlogun (15 Minutes)
Dosage: A glass cup 2 Times daily.

(2) CANCER /PROSTRATE, THE KILLER DISEASE
OSAN WEWE MERIN; (LIME) a o ge si meji a o se daradara. Dosage a o ma mun ni gbigbona ti yio maa jo wa ninu ati lenu gan. 2-3 times daily. Please very effective.

(3) LOW / HIGH B/ P; EWE PEAR A o se fun 20- 25 Minutes.
Dosage ; a glass cup two times daily Please after THREE days go and check you B/P

(4) DIABETES IS A DEADLY DIOCESES"

Powder OSAN AGBALUMO / ATI POWDER ABEERE, A o wa omi AGBON (COCONUT WATER) ONE BIG BOTTLE OF TABLE WATER A O BU SIBI MEJI MEJI (TWO TWO SPOONS) si nu re. To ferment for 3 days.
Dosage ; a short (smaĺl cup) drink twice daily until you finish the bottle.

(5) Oyi OJU, OYI ORI ATI OYI INU. A O WA EWE (IYEYE) A O JA A.
A O gboo daradara, A o fi IYO DIE si. Small SAULT.
Dosage; a glass cup 3 times daily

(6) AGBO JEDI-JEDI TO MU NA DOKO.
EEPO OKURU-KURU, PELU ALUBOSA AYU ATI KAFURA. A O FO NU A O KO SINU KEG TO NI IDERI FUN OJO MEJI (24) HRS
Dosage a glass cup two times daily. Kii ya enia ni igbe rara...

7. OGUN ROPAROSE - STROKE TODAJU

Owo iwaju Aja ati ese eyin Aja mejeji. odindin Atare Aja kan. E jo gbogbo re papo, E o sin gbere yika orun Owo ati Ese yin mejeji ati Orikiriki gbogbo Ara. Ki e wa fi Ebu naa kun oju gbere naa daadaa.

8.OGUN ARA TITA Ati ESE TITA

Osan Jagain Mewa (10), Osan Oronbo mewa (10), e o ge awon Osan naa si mejimeji. Ewe Ireke tutu. E o fi Omindun se awon Eroja naa, ko jina daadaa. Ki e maa mu Cup meji lojumo.

9.OGUN JEDANJEDAN - CANCER LIVER

Eso Taba pupo die, Odindin Oga gbigbe kan. Eyin Ibile mefa (6), Odindin Atare kan. e jo gbogbo re papo. ki e lo, ko kuna daadaa. ki e wa da EBU naa si ADIEYAN. Ki e maa mu Sibi kan laaro ati Sibi kan ni Ale.

10. 0GUN WARAPA TODAJU - EPILEPSY

Omonle Aiye kan, Epo-Obo die, Odindin Atare Aja kan, e jo gbogbo re papo. ki e da Ebu naa sinu Oti Ogogoro tabi Shinapp. Ki e maa mu Cup kekere kan laaro ati lale (Twice in a Day).

11. OGUN GIRI AGBALAGBA ATI OMODE - CONVULSION

Eku Asin gbigbe kan, Iseta, Ewe Taba tutu, Ewe Kataba gbigbe. Ewe Taba Oyinbo, Alubosa Elewe, Ewe Taba Juku, e re gbogbe Eroja naa sinu Oti Ogogoro tabi Shinapp. ki e maa mu Cup kekere meji lojumo. (Twice in a Day.) tabi ki e lo gbogbo Eroja yen mo Ose dudu ki e maa fi Ose naa we laarolaaro.

12. OGUN ATOSI - GONORRHEA

Epa Ikun, Bara, E o be Bara naa. e o yo gbogbo koro inu re danu. E o ge kekeke sinu Ike funfun. E o fi Oti Ogogoro re fun (4 days). E o ma mu Cup kekere meji lojumo. (Twice in a A day).

13. EDA OBINRIN - VIRGINAL DISCHARGE

Osan wewe mejila (12), e ge si kekeke, Atale tutu, Alubosa Ayu tutu, Ewe Efinrin pupo. E fi Omi se gbogbo Eroja naa, ko jina daadaa. ki e maa mu Cup meji lojumo, (Twice in a Day).

EDA OBINRIN - VIRGINAL DISCHARGE

Ewe Dasa gbigbe pupo. e lo, ko kuna daadaa. Ki Obinrin maa fi fo Eko mu laarolaaro. tabi ki e lo Ewe Dasa naa mo Ose dudu, ki Obinrin maa fi Ose naa fo Oju Ara re.

14. OGUN IKO - ASTHMA

Odindin Oga gbigbe kan, E lo ko kuna daadaa, Ki e da sinu Oyin Orijinal, ki e maa mu Sibi kookan lojumo (Once in a Day).

15. ATO TO SAN- LOW S***M COUNT

Oyin Sibi merin, Eyin Adie Agric merin, Pilk Milk kan, E o da gbogbo re papo sinu Cup, Ki e gbe gbogbo re mu lekan. Ki e maa mu ni emeji laarin Ose (Twice in a Week).
E jeki a share rẹ fún anfani ẹlòmíràn
Copied

13/06/2023

Akiyin kaabo sí ojú òpó asiri ewe ati agbara egbo, fún itusile ati ida nde omo niyan, ki eledumare kun igbiyanju enikookan wa lowo,esi je ki eni kọọkan wa ma gbiyanju lati ma share gbogbo anfani ti aba nba pade loju òpó yin, fún anfani ẹlòmíràn, Aajuwaa seo

Address

Akódá
Osun
100011

Telephone

+2348149567694

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri ewe ati agbara egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share