Ọla adua healthcare 001

Ọla adua healthcare 001 Solution to all problem prayer and herbal medical center WhatsApp 09159185940
(1)

OGUN FUN PROMISE AND FALLOla adua 09159185940Oga gbigbe 1, efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, od...
26/08/2026

OGUN FUN PROMISE AND FALL
Ola adua 09159185940

Oga gbigbe 1, efun ado, osun buke,imi ojo, ikumu ojia, ewe areyin kosun, odidi atare ao
jo papo ao fi omi agbon pomo ose dudu ao kosinu fitila oloju kan ao wa te ifa ogbe fun
(ogbe ofun) si ori ose na lori
NB inu fitila oloju kan lama ko ose yi si lao sese Wa te ifa yi si lori ao mafi we odaju
Promise and fail yio da gbere ninu aye enina

IFERAN GBOGBO ENIA TODAJUBy: Alfa ola adua 09159185940Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna ...
23/08/2026

IFERAN GBOGBO ENIA TODAJU

By: Alfa ola adua 09159185940

Ewe Awerepepe, ewe Taba ibile, Igbo mimun, ori ijapa, ao gun kuna daadaa, ao da sinu
lofinda eyikeyi ao maa fi paa oju tabi gbogbo ara. Awon Enia yio maa ni ife waa pupo

IMULE ELEYE TI AOMA BAWON SORO LOJU KOROJUBy:Alfa ola adua 09159185940EYE EGA AYE AOLO LORUN PA EMA JEKI EJERE DA SILE O...
22/08/2026

IMULE ELEYE TI AOMA BAWON SORO LOJU KOROJU

By:Alfa ola adua 09159185940

EYE EGA AYE AOLO LORUN PA EMA JEKI EJERE DA SILE OOOO EDE MAJEKI EJE JADE
RARA OOOO AOKI IKOIDE BO LENU AOKO SINU APE TUNTUN PELU ODIDI ATARE KAN
TABAJOTAN AOFI TE EJIOGBE AOPE OFORE SI.. AO WA OLE ELEPO META AKARA
ELEPO META EKURU FUNFUN META AOKO SINU AWO IPESE .AOTIRO EBU YEN SINU
ADO IJAMO AONIDE LENU AOWA GBE ADO NA SORI IPESE YI AOGBE SEYIN KULE
TOBA DI ARO OJO KEJI AOLO GBE AJEKU AOJO PELU ADO NA AORO SINU ADO
MIRAN AO MA FI FOKO MU LALARA OOO OJO META META. .FUN OJO KAN GBAKO
AODE BODO SU OBINRIN
OFORE.
EMI L OMO L TIBBA EYIN ELEYE FUNFUN MULE LONI KEWA JAWO LARA KE WA MA
BAMI SORO LOJUKOROJU KEWA FI ILE MI SE GBUGBE TI OHUN KOHUN BAFE SELE
KEWA MA SO FUN MI

ASIRI TI ANFI GBA KADARA WA PADA NIBI KIBI TO BA WA... Alfa ola adua 09159185940 Akoko, ao wa adaripon kan, ao fi epo ob...
21/08/2026

ASIRI TI ANFI GBA KADARA WA PADA NIBI KIBI TO BA WA...
Alfa ola adua 09159185940

Akoko, ao wa adaripon kan, ao fi epo obo die le laya, ao fi egbo tude kan le, ao fi eru alamo si, atare kan le, ao wa fi owu di mo ara adaripon awa jo. Ao pin si ona meje...LILO RE... Ao to sinu cup kan ni idaji ki ato soro si enikankan, ao fi lo ebu yi. Ao se be fun 7 days...
EKEJI...Ao wa eso werenjeje 21, ao pa, ao yo tinu re funfun jade, ao wa lo kunna dada, ao fi singbere yipo ikun ati yiko apa. Yio da gege bi komu obinrin...

NOTE... Eni ti ofe singbere ati eni ti yio sin fun eniyan won gbudo koko laa epo pupa ni emeta. Ori ikunle ni awon mejeeji o si wa ti won o fi sin tan. Aoti koko fi epo pupa ra awön ibi ti a fe singbere na si ki a to sin..IRE, OGO, ATI KADARA RE YIO PADA S**O RE. IKU SIN BE FUN ENI TOGBA TELE TABI ENI TOBA FE GBA.

01/08/2026
16/07/2026

Ogun ti afin gba agbára lọ́wọ́ obinrin wa
By Alfa Ola Adua 09159185940

OGUN TI A FI NGBA AGBARA LOWO OBINRIN WAEpo iginla, epo obo, ewe olubori, ata wewe pupo, ao ja awon ewe re ao lo po aowa...
16/07/2026

OGUN TI A FI NGBA AGBARA LOWO OBINRIN WA

Epo iginla, epo obo, ewe olubori, ata wewe pupo, ao ja awon ewe re ao lo po aowa mu eye ina soju olo a obu omi pa pelu gbolohun yip e:- Omi ni nporo ina gbogbo nkan ti obinrin yi ba fin se agbara ko ku ko wole loni, ao po mo ose ::- LILO RE

Alfa Ola Adua 09159185940

08/07/2026

Watch, follow, and discover more trending content.

06/07/2026

Aseje stroke
By Alfa Ola Adua 09159185940

Address

HEAD OFFICE: JOLAB LIADI Avenue NO 14 OFF YEWA ROAD ODO EGIRI EPE LAGOS STATE BRANCH OFFICE BEHIND K. S HOTEL OROKI OYO
Oyo

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ọla adua healthcare 001 posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category