04/02/2026
IF YOU DON'T UNDERSTAND YORUBA, INGNORE THIS ARTICLE.
¤OFO ITAJA(AFRICAN PSALM FOR BOOSTING SALES)¤
FUN AWON TI NTA OJA :- Ao pe ofo yi sinu iyo(cooking salt), ao wa won sibi ti ati nta oja.
FUN AWON TI NGBA ISE:-
Ao pe sinu omi, ao gbemu.
OFO
Owon owo laa na'wo kinkin.
Owon omi laa le'sun.
Owon onje laape ni'yan.
A difa fun Ohun-yio-won, omo oba l'Eyo-a-j'ori.
Ti nwon ni oja re ko ni kuta.
E sare wa raja omo-oba.
At'ewe at'agba ni i raja eyi-o-won.
E sare wa raja omo-oba.
Ogberi ni ite, awo ki ite!.
O difa fun pankere ti mbe lawujo ore.
Ifa ni pankere o ma niite!!.
Esare wa raja omo-oba.
Gbogbo eniyan ni i sare raja eyi-o-won!.
E sare wa raja omo-oba.
E sare wa ba emi Odunoren Adebowale Psalmist raja temi,
Tomode tagba ni sare ra oja eyi-o-won.
E sare wa, ewa ra oja oba Eyi-o-won o.
Coming soon with the uses of the talisman below…………..
Shalom