Agbesinga agbaye

Agbesinga agbaye DR. AGBESINGA AGBAYE SPIRITUAL AND NATURAL HERBS REMEDIES
HERBS� DOCTORS, HEALTH MOTIVATIONAL, SPIRITUALISM, ISLAMIC LECTURE, MOTIVATIONAL SPEAKER. BLOGGER
(4)

24/07/2026
MIO O FE Mo IRU ORI TI EYAN LE GBE WAYE, bi eyan bale se asiri yi onitohun yori  owo gidi ati anu ninu osu yen ..kabiesi...
22/07/2026

MIO O FE Mo IRU ORI TI EYAN LE GBE WAYE
, bi eyan bale se asiri yi onitohun yori owo gidi ati anu ninu osu yen ..kabiesi re Olorun, mafi oju Di asiri yi, bi eyan bale se asiri yi oro onitohun Koni ye araye Bose RI Owo ati anu gba, mafi oju di asiri yi rara ..asiri yi daju gan nio, ..sungbon wa gbo mi loni oo ranti ojo ti yo ku Iwo ati e le da re ninu sare kosi ranti ese mefa ..Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ese mefa, ( ki eyan Fi 500 thousand se Ajo kole daju ju bayi lo ,aro kutu tabi ale ni ao se asiri yi,. Ao bu omi ti ale fi Sanra kale, ao wa lo wa odidi isana eyo kan ,okunrin yio yo eyo mesan ninu isana na obinrin yio eyo meje ninu isana na ,ao wa ma sa isana yen ni eyokankan ti aba ti sa isana na ni eyo kankan, ao ma ju sinu omi tabu kale na, t**i tafi sa isana na pe eyo mesan, obinrin na yose tie be t**i isana na yofi pe eyo meje, ao wa da iyo die sinu omi na ao wa ma sadura si omi na pe omi ni poro Ina gbogbo idiwo ati idina tibe lara mi ki omi yi poro re loni oo lati oni gangan lo kiri bere Sini ri owo na kiri ile aye gbe pelu irorun,ti o ba fe ko sise fun koko coment ko de share re naa,fun anfani elomi,,taba ti gbadura si tan, ao wa lo fi omi na San Ara wa , ahhh asiri yi daju gan o,bi eyan ba se asiri yi oro onitohun Koni ye araye Bose RI Owo ooo ,asiri yi daju pa...

ANU OLORUN KOMA BAYIN GBE OOOThanks for being a top engager and making it on to my weekly engagement list! 🎉 Samson Omo ...
21/07/2026

ANU OLORUN KOMA BAYIN GBE OOO
Thanks for being a top engager and making it on to my weekly engagement list! 🎉 Samson Omo Yoruba, Alatake Michael, Akins Akins, Hardey-yemmy Qozeem, Edmond Chemin D'or Houngbedji, Adekola Musiliu, Khadijat Adenike Adeleke, Latifat Aderonke, Roukayat Raouf, Oshinlade Sunday, Nasir Oladipupo, Ummu Sekinah, Adeola Abdulrasheed, Afolabi Sikiru, Oladipo Oladipo Debora, Olanrewaju Yushau Adewale, Balogun Risikat, Ogunmosu Kehinde, Afolabi Balikis, Idowu Noble, Ollatunji Motunrayo, Mujidat Abiola, Alex George, Rofiat Alake, Ganiyu Jimoh, Yemisi Fajemilua, Ademoo Omotoso, Adedeji Adeyemo Aka Wisam, Bola Olagunju Bammeke, Adijat T**e, TaoFeeq Wabilah Olalekan, Ismail Safurat, Benjamin Tope Bridget, Abisola Mutiat, Jumoke Okunola, Abbey Olohunshola, Hanafi Bola Babatunde, Fatimoh Aduagba, Temitope Ganiyat, Momsy Abike, Abosede Adeyinka, Kabirat Abodunrin, Alade Sheriff, Genesis Dorisy, Oriyomi Monsuru, Oduyemi Olayinka Mattew, Fausat Olalekan, James Olaniyan, Alabede Suliat, Kenny Richie Artists

ERU OLORUN MA TUN BA MI OOO ...enikeni tiko bati se Ori re lati ara asiri yi walahi mi ro pe eni be le sori re mon .. ey...
21/07/2026

ERU OLORUN MA TUN BA MI OOO ...enikeni tiko bati se Ori re lati ara asiri yi walahi mi ro pe eni be le sori re mon .. eya tete so fun iru enibe wipe ati sori re enibe di Owo Olorun Nikan .. ki eyan pa odidi eyan kole daju to asiri yi ahhhh eru Olorun ma tun bami oo .asiri wa ooo ...sungbon wa gbo mi loni oo ranti ojo ti yo ku Iwo ati eleda re ninu sare kosi ranti ese mefa ..Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ese mefa ...ki olorun wo ola Inu kan ti mofi se awon eyan lore ki o san emi na nii esan rere ..(. eleyi kise a*odun rara ooo ..ase Olorun gan gan ni asiri yi, ahhh eru Olorun bami pupo Lori asiri yi ,ao lo wa orogbo eyo kan pere,ao wa bu omi sinu cup kan, ao wa ju orogbo na sinu omi na lati ale, ti o ba wa di 12am ao se adura gbogbo inkan ti Ako ba Fe Mon ninu aye wa sinu omi ti aju orogbo na si , leyin na ao lo sun ti o ba wa di idaji kato soro si enikeni ao wa lo gbe omi na, ao wa se adura gbogbo Inkan ti aba Fe si omi na ti aju orogbo na si,ti o ba fe ko sise fun o koko coment ko de share re tori fun afani awon elomi na ni, leyin ti aba ti gbadura si tan ,ao koko mu orogbo towa ninu omi na jade ao wa mafi orogbo yen nu ori wa ao ma se adura gbogbo ohun rere taba fe leyin na, ao wa fi omi na towa ninu cup yen fo Ori wa lesekese ,ao wa ju orogbo yen nu, ti eyan bari asiri yi se aye onitohun tida patapata niyen ooo,

19/07/2026

ITUWO AWON AGBALAGBA

Igi nla, epo obo, eru awonka tikokan rara , epo igi ose oojo, ao gun pomo ose dudu ,oronro malu lao fi po papo, a*o egungun lao fi maa we (a*o egungun ni Konkon re) odaju lase edumare 🙌🙌

17/07/2026

INA OGO WA KONI KU OO

16/07/2026

MOFI ISE YI SILE NITORI AWON ILORIRE ENIYAN, TI ORO AYE WO JOWON LOJU
ISE È LEYI TUN YATO SI GBOGBO ISE OO, BE SINI ISE YI JU KI O WE OSE LO TABI JE ASEJE, ASIRI WA, BE SINI AGBA ONI TAN LORI ILE .
ma dawo duro ki o ma ba wa aye asan, iye awon eniyan ti olorun ti lo mi fun lati ori Facebook koni oun ka rara ki olorun oba ki o San mi ni esan rere gege bi inu kan ti mofi fi awon ise ijinle sile , gbo mi loni ranti ojo ti yo ku Iwo ati eleda re ninu sare kosi ranti ese mefa .. Fun Iwo scammer ti o bà aye awon eyan je Lori Facebook tosi nlu won ni jibiti, Iwo na ranti oo kosi ranti ese mefa, asiri yi daju gan oo, sugbon olorun daju ju lo
Ise yi ko na wa lowo rara,ni ale tabi aro ao bu Iyo owo kan ao se Adura ohun ta fe sinu Iyo na, ao pa ese wa mejeji pa po Mora won, ao da Iyo na si arin Ese wa, ao gbadura ki Irinajo wa koba alanu pade, ti o ba fe ko sise fun o Koko comment ko de share re tori fun anfani awon elomi naa ni,,Leyin ti a ba gba adura,ao wa da iyo naa sinu omi toto wa we,ao wa fi omi naa sanra lesekese,,afi eniti ko ba coment to de share re lo tun le saroye lehin asiri yi

HAPPY BIRTHDAY TO ME AM + 1 TODAY
13/07/2026

HAPPY BIRTHDAY TO ME AM + 1 TODAY

12/07/2026

MADURO SOJU KAN KOLERI AIYESE OO
FUN IWO TI NKAN O LO DEDE FUN,FUN IWO TI O TI GBIYANJU T**I TI KOSI AYIPADA FUN O, FUN IWO TI WON O JE KI ASIRI SISE FUN O,FUN IWO TI O NILO ALANU NI KIAKIA, ASIRI ELEYI NI KO TETE LO GBIYANJU NISIYI, RI DAJU WIPE O KOKO SHARE RE TO DE COMMENT TO LE SISE FUN O DADA O
ni ale o se eyin ibile tabi eyin agric eyokan,ti o ba ti jinaa,ao bo epo ara eyin naa,ao da epo eyin naa sinu omi iwe wa, ao wa fi iyo die si,,ti o ba fe ko sise fun o koko coment ko de share re tori fun afani awon elomi na ni, ao wa lo fi omi yen sanra lesekese,lehin ti a ba fi omi yen sanra tan,ao wa mu eyin ti a bo epo kuro lara re yen,okurin yo pe oruko re si nigba mesan,obirin yo pe oruko re si nigba meje ao wa gbadura ohun ti a fe si, ao wa Je,,ao wa lo sun,,kosi bi ogun se le po to walahi bi eyan ba se asiri yi onitohun yo dupe fun Olorun

Address

Lagos

Telephone

+2348061677730

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Agbesinga agbaye posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share