27/09/2026
AGBARA NBE NINU ISLAM FUN ARISIKI TODAJU, KOSI EYA TABI ESIN TIKOLE LO ISE YI
KI IKE ATI OLA KIO MABA ALFA WA TOYANDA ISE NA FUN WA
ASIRI TÍRÀ TI OWÓ KI FI TÁN NI OWÓ ENIYAN
ÀSÍRÍ TÍRÀ YÍ JÉ ÀSÍRÍ KAN TIO CONFIRM DAADA, NÍNÚ ÀSÍRÍ ÀWON ÀGBÀLAGBÀ Y
TIO YANJÚ GIDI NI, ÒPÒLOPÒ ÈNÌYÀN NI YIO MAFI OJÚ KÉRÉ TÍRÀ YÍ, SÙGBÓN TÍRÀ NAA KOJÁ BE, GBOGBO ÈNÌYÀN NI TÍRÀ YÍ WÚLÒ FUN, BIA BÁ PARI TÍRÀ YÍ TÁN BIA BÁ BÈRÈ SÍNÍ LO HAAAAA OWÓ O NÍ TÁN LÓWÓ WA, AO NÍ NA ÒKAN TÁ KIA TÓRÍ ÒMÍRÀN, OMODÉ PÈLÚ ÀGBÀ NI YIO MAFI OWÓ SANU FUNWA, ISÉ TII GBOGBO WA TII AO SÁRÉ LOSE NÍ KIAKIA NI.
SÍSE ISÉ TÍRÀ NAA.
AO HAN TÍRÀ NAA SÍNÚ PAPER FUNFUN KAN PÈLÚ BLACK BIRO, AO KAN LOFINDA TIO BÁNÍ OORUN DAADA SÍ AARIN TÍRÀ NAA, AO WAFI OWÓ TIO BÁ GÁJÙ NÍ ORILEDE TIA BÁWÀ SÍ ORÍ RÈ, AO KÁ TÍRÀ NAA PAPÒ MÓ OWÓ NAA, AO WENÍ ÒWÚ FUNFUN, AO TÚN KAN LOFINDA YAN SI LÁRA LÉYIN TIA BA WE TAN.
AO MAJU TIRA NAA SINU APO TABI POSI WA TABI INU APO ASO TANKO OWÓ SI.....