Ewe ati egbo Ogun ibile todaju

Ewe ati egbo Ogun ibile todaju Ona abayo fun orisirisi aisan ati igbiyanju eda.

01/02/2026

OSE ANU ARINAKORE TODAJU GIDI CONFIRM NI ISE YII....

ISENA RE:-
OSE JOY TABI LUX META TABI MEFA
AGBON NLA KAN
OYIN ORIGINAL
ESO WERENJEJE LOPOLOPO
WHITE HANDKACHIEF
IKE FUNFUN

SISERE:-
FARABALE DADA OOO, AOGUN ESO WERENJEJE YI KUNA DAADA, AOFI OMI AGBON DIE REN OSE YEN AOWA GUN ESO WERENJEJE YEN MO RAWON AOFI OYIN PO AOKO SINU WHITE HANDKACHIEF AOWA SESE WA GBE SINU IKE FUNFUN YEN AODE PA FUN FIVE (5)DAYS. KO GBODO KANLE RARA OO

AKIYESI: TOBAJE CHRISTIAN NI ENI TONI OSE YI YIO KA PSALM 46 SINU RE 7X, SUGBON TOBAJE MUSLIM NI ENI TONI OSE YI YIO SE ADURA PELU QURAN SI. TESTED AND CONFIRM

LILO RE:-
AO MAWE LARO MONDAY, TUESDAY, THURSDAY, SUNDAY,

IWO TI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE ABI TI O MA BI OSE FESE MOLE SE FUN YIN, DM

FOLLOW MI LATI JE AWON ORISIRISI ANFANI TOPO NIPA BI ASE NLO EWE ATI EGBO FUN IWOSAN ATI FUN ONA ABAYO.

OGUN IKIYA.AO WA OJU OLONGBO MESAN EYO ATARE MESAN, EYO OKA BABA MESAN, AO LO PAPÒ, AO FI SÍNGBÉRÉ META-META SI AYA PELU...
01/02/2026

OGUN IKIYA.

AO WA OJU OLONGBO MESAN EYO ATARE MESAN, EYO OKA BABA MESAN, AO LO PAPÒ, AO FI SÍNGBÉRÉ META-META SI AYA PELU EYIN.

IWO TI ISENA BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE ABI TI O MA BI OSE FESE MOLE SE FUN YIN.

24/04/2025

FUN IWO TI O KO RI NKAN ALEJO REMO TI O KO SITI DI ARUGBO

1) Egbo tude, kanfo, ewe tude tutu, ao lopo sinu omi osan lakuregbe, ao wa SE Lori ina, ao ma je asaro( ebe) tele inu kia to wa mu agbon cup kan Le Lori.
2)ewe esunsun pupa, epo oruwo, osan, kahuna, alubosa, epo, ao fi omi dun sepo, cup kan laro laro.

ODAJU!!!

24/04/2025

EYONU OWO!!!

Agbon meji ao jo omi inu re, ao fi omi inu re yen gbo ewe sinkinmini, ao yo omi na, ao da lofinda tabi perfume toba wuwa si, ao fi #1000 tele igun ile, ao wa gbe ogun yen le lori, ao wa fi epo obo le lori, ao wa ma fi para losi ibi ise wa.

Fun iwo tio ko ba le SE fun rare, o wa fun tita
ODAJU!!!

16/10/2023

Ohunfa kositoma!

Iwo tio bani shop tabi ile ise nla , Alfa tabi pasito nio ni ise yii.
Gbiyanju lati wa kanhinkan ibile iyekiye, ao jo pelu odidi atare kan, ao lo efun mo, ao ro sinu ado kan, ao jipo daada, ao toju re pamo sinu ile ise wa, to kositoma bati dide lori ibi tio joko SI, ao mu ao ta die si ori aga tabi eni tio ti dide,

Fun iwo ti o kole se ise yii fun ra re, o wafun tita lowo tiko gunpa, WhatsApp+2348128100596

16/10/2023

As Sugar Attracts Ants......So shall your hands will attracts plenty money from today.i solve problem like..

*Instant Money
*Married issue
*Business Boom
*Court Case
* promoted at work
*Spiritual Husband

if you need my help,in any kind of spiritual problem, call me on+2348128100596 or message me on Whatsapp,

16/10/2023

ENI OJO AJE!!!
It's Monday it's new week
Good thing shall locate you today
What so ever you lay hand upon today shall prosper
Eledumare open new door for you today
AJE Olokun oguguniso,oniso iboji
Aje alaso ala funfun gboooooo
Aje ko sare tete wa je wa
Awa oni se eru AJE l'ose yi ooo
Ta ba ti nnawo a ma ri mu
Ta ba ti nla enu a ma ri pe
Aje ko je wa ni gbogbo ona
Ose yi a san wa oooo
A oni ba ode pade
A oni jade le iku lowo
Ayunlo ayunbo ni owo nyun enu
Ina ogo wa koni ku
ASE NTEDUMARE
ONFA KO FA IRE AJE WA FUN GBOGBO WA
ASE OOOOOOOOOO!!!!!!

Address

Oyo
Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Ewe ati egbo Ogun ibile todaju posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share