Aiyemojuba Spiritual HOME

Aiyemojuba Spiritual HOME This is a page that deals with human and their spiritual life, with the uses of herbs and roots.

02/01/2026

Esu Alaje 😏 is often associated with wealth, prosperity, and good fortune 💸. He's believed to bring financial success and abundance to those who honor him 🤝.

E KU ỌDÚN Àsọdúnmọ́dún níí ṣ'Awo Àsọdúnmọ́dún Àsoròmórò níí ṣ'Awo Àsoròmórò Ìtí igi, a sùn má pa'hàdà, Adifá fún Ọ̀làlà ...
01/01/2026

E KU ỌDÚN
Àsọdúnmọ́dún níí ṣ'Awo Àsọdúnmọ́dún
Àsoròmórò níí ṣ'Awo Àsoròmórò
Ìtí igi, a sùn má pa'hàdà,
Adifá fún Ọ̀làlà tíí ń ṣ'Awo rè'lú ọ̀bẹ
Ẹbọ ni wọ́n ní kí o ṣe
Ósì gb'ẹ́bọ̀ níbẹ̀, ó ńtu'bọ̀
Ẹbọ rẹ̀ sì dà ládàjù
Lóbá lanukótó, loorin Awo bá kó síi lẹ́nu
Ó ńwípé Ọ̀làlà lawo ọ̀bẹ òoooooooo
Ọ̀làlà lawo ọ̀bẹ,
Atila ọdún yìí já,
Aó tún la tẹ̀ẹ̀mí-ìn
Ọ̀làlà lawo ọ̀bẹ,
A ti la ọdún tó lọ́ já
Aó tún la èyí náà já,
Ọ̀làlà lawo ọ̀bẹ.
Aiyemojuba Trado-Medical Center nki gbogbo wà pe aku ọdún tuntun ooooo

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Aiyemojuba Spiritual HOME posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category