CHIEF Arijelagbin

CHIEF Arijelagbin Wa fun iwosan aiyelala,itoju omode ati ebe fun awon agba,wa fun ayewo nkan to ba ru o loju
call me 08060335132 or 07033178984

12/01/2025

Isese day 2024

19/01/2023

ogun ajobo day

OGUN AJOBO
10/07/2022

OGUN AJOBO

31/05/2022
17/02/2021

TIRA IBON TODAMILOJU DAADA
Ao wa ori ako alangba eyo kan, ao wa egusi sofi, tintintin bayii nima nri awon elewe omo nta daada, eyo 16 lama lo, orogbo kekere, ao ge ori alangba yii ati owo osi re, ao wa ko egusi eyo 16 yii senu alangba naa, ao fi orogbo kekere yen senu re, ao tunfi owo osi re senu re bakanna, ao gbe sinu a*o dudu, ao fi owu dii papo, ao wa lo ran ni odi awo dudu, ao ma fi sara, owo buruku yio ma je funwa, asita ibon

11/01/2021

( AWURE OWO NI ) ORI OKA TONI ASE 3. ORI OLUFA TONI ASE 3. ORI OFAFA TONIRUN 3. ORI AGILINTI 3. EYE KOWE META. EYE ALAGBEDEORUN 3. EYE LEKELEKE 3. EYE ELULU 3. OWO TUNTUN 3. AOKO GBOGBO WON SINU APE TUNTUN TOTOBI DADA AOKO EWE EYINOLOBE BO LORI AOWADA OTI LORD IGO META SI AOWAGBE PAMO DI OJOKEJI INU IGBO LAOTIJO AOLO AORO SINU SERE TOBAJEPE ENIKAN SOSO LOFEMALO BUT TOBAJEPE ENIYAN PUPO NI AORO SINU IGO AOWAPIN LILORE TOBAJEPE ENIKAN NI YOMABU SI ATELEWO YOMAFI OTILO TOBAJEPE ENIYAN PUPO NI AOBU SIBI MEJI SINU IGO OTI KAN AOMAMU LARO LARO

10/01/2021

Ao lu ori eyin adie ororo kan,ao ko gbogbo omo inu atare sinu eyin na,lai jekio bo danu rara,ao so sinu ora,ao so lenu,ao fi ito alaboyun se eyin na jina,ao je eyin na.ao ko epo eyin na sara nkan elemi,ao yin ibon si wo-odaju kole ba rara

10/01/2021

AGADAGODO IFE TODAJU

Ela ileke die,
Obi lakiriboto,
Orogbo kan,
ODIDI atare kan,
AIDAN kan,
AO jopo ao fisi efe owu
A ofi owu dudu ati funfun we mo eyin agadagodo.
Ofore!
Lakiriboto ki loju awe, ela ileke ki loju atokunbo, aidan ki roju ati sun ki L omo L koma ri oju ati sun koma wa emi L omo L.
A ó ti pá. A ó lọ sọ s**o ńlá.
Ire ooo!

27/10/2019

ATUDE
* Ewe lapalapa funfun mesan
* Ewe ewuro oojo mesan
* Ewe efinrin oojo mesan
* Ewe ajeobale oojo mesan
* Iyepe ago kan osan die
* Iyepe ago kan oru die
- A o gun awon ewe yen ninu odo daadaa
- A o lo awon iyepe mejeeji yen lori olo kunna daadaa
- A o wa eyi ti a lo lori olo yen si inu eyi ti o wa ninu odo
- A o wa gun gbogbo re papo mo ose to ba wu wa.
- A o pin ose na si ona meta pere
- A o fi ose na si ara kainkain tuntun meta
LILO RE: A o ma fi we ni ago kan oru fun ojo meta gbako
AKIYESI: Ti a ba tin we ose yi tan a o ma tu kainkain ti a fi weka, a o si ma ju sonu
ASHINA AWON AGBA
* Ako alangba tutu tabi gbigbe meje
* Abo alangba tutu tabi gbigbe meje
* Eye onbe tutu tabi gbigbe meje
* Esuru pupa, a o ge si meje
* Odidi atare meje
- A o jo gbogbo re po ninu ape ijonkan
- A o fi adin dudu po ebu na po mo ose to ba wu wa,
- A o ma fi omi gbigbona we ose na ni ale patapata laijade mo rara.
AKIYESI: Awon ise mejeeji yi ko se pin lo rara. Nipa ti ose ashina yen, iye ojo to ba wu wa ni a le fi we, o wa lowo bi ose na ba se po tabi kere si, atipe kainkain kan soso ni a o ma fi we ose ashina yen t**i ose na yio fi tan.

04/09/2019

OBINRIN TI KO RI NKAN OSU RE MO
Iye akuko,Ikoode kan,Poporo oka baba, Osun bike, Iyo isebe die
Ewe owu akese, Epo amuje, Egbo oruwo, Egbo laali.A o gun po , a o se ni powder , fi fi mu eko gbigbona.
OBINRIN TI KO RI NKAN OSU RE MO
Gbogbo ifun ati edo abo adie ti o ti npamo ri, Egbo akoko , a o bo epo re, Ata ijosi , iyo isebe , a o gun po , a o se ni powder , fi fi mu eko gbigbona.
OBINRIN TI KO RI NKAN OSU RE MO
Poporo oka baba, Egbo oruwo, Epo amuje, Ikoode, Itanna ori ido lopo.A o gun po , a o fi ma mu eko gbigbona.
OBINRIN TI KO RI NKAN OSU RE MO
Eso werenjeje, Osun bike, Poporo oka baba.A o gun po , a o da sinu ike kan , a o ro omi si , mimu diedie.

Address

Ibadan

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when CHIEF Arijelagbin posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Share

Category