The most powerful herbalist native doctor

The most powerful herbalist native doctor +2349014572744 call me for any spiritual assistance

AWORO ALARIMOLE TODAJU..+2349014572744Mofi olorun bura wipe enikeni toba lo iseyi yio mon wipe titobi ni olorun, o dara ...
19/10/2024

AWORO ALARIMOLE TODAJU..+2349014572744

Mofi olorun bura wipe enikeni toba lo iseyi yio mon wipe titobi ni olorun, o dara lopolopo fun onise owo, Onisowo, ile-ise, ijo olorun ati bebelo, o damiloju wipe ero konida nibikibi ti a ba se iseyi si, besini ko nawa lowo rara, danwo ni o yin olorun..

ISENA RE:-
Ogede omimi pipon mefa ao bo epo arare danu ao ko sinu ike kan o fi Owo fo papo Dada ao fo eyin adie ibile kan si ao fi po papo ao wa bu iyo die si ao fi po papo naa ao wa sese lore da sinu koto tia gbe sinu shop tabi abawole inu shop wa ao wa da igo epo pupa le lore ao wa fi bi afoku apadi bo Lori ao wa se adura si ao wa sese roo yerupe bo monle mofi ojo ti yoo ku emi nikan ninu sare mi bura walai aworo toni agbara ni.. 09014572744

OSE ANU TODAJU TI KOSI NAWA JU  #500 LO+2349014572744Ise yi daju debi wipe ale fiwe omo tuntun, ati iya omo naa, won yio...
23/06/2024

OSE ANU TODAJU TI KOSI NAWA JU #500 LO
+2349014572744
Ise yi daju debi wipe ale fiwe omo tuntun, ati iya omo naa, won yio gba ebun debi wipe yio sun won,
eyin te n sise owo tabi eyin te nta oja ti enu se aroye pe ko si oja ko si owo egbinyanju ise kekere yi wo

OSE ANU
( 1 ) OMUNU EWE EWURO OOJO
( 2 ) KANFURA PELEPE
Ao gun mejeji papo ninu odo ao ju ose sinu re ao gun papo lai fi omi si ao ko sinu ike funfun ao gbe pamo si ibi ti ko si egbin ao ma fi we larolaro

SE AYEWO LORI ORO AYE RE, LORI ISEDA RE KOLE MO IRU AYANMO TO GBE WAYE ATI ONA ABAYO

IKILOPATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare

ENITI ISE YII BAWU LATI SE SUGBON TIKO SI AYE TABI TIKO MON BIO SEFESE KIO MESSAGE MI LORI WHATSAPP ((09014572744)) ALE RAN YIN LOWO LATI BAYIN SE

FUN IBEERE TIONI ITUMON ATI FUN IRANLOWO ONAABAYO SI GBOGBO ISORO AYERE CALL OR WHATSAPP TIOBA NIGBAGBO (( 09014572744))

Se enikan le fi ohun ton se sile lati se amin meta toni ina ninu kiosi share re si group meta pere Okun tikosee di igi t...
23/06/2024

Se enikan le fi ohun ton se sile lati se amin meta toni ina ninu kiosi share re si group meta pere
Okun tikosee di igi tia fin gbare mo o lowo
Okun tikosee di igi tia fi mu o so bi eran
Okun tikosee di igi tia fi de ogo abawaye re
Okun tikosee di igi taye fi de o sojukan
Okun tikosee di igi tiafin ko o ti onde o lona ati serere
Okun tikosee di igi ti a fi de igbeyawo re
Okun tikosee di igi tiafi de o mo igbekun
Okun tikosee di igi ton sise amubo ninu aye re
Okun tikosee di igi taye fi de iserere re
Moduro mioda duro mosoro mioda soro mowi loruko oluwa toda aye ati orun okun naa loni ina orun ko gba larare loruko jesu

For prayer and councelling consult my number 09014572744

ISE EYONU AwON AGBA, TI ALE FIRI OWO LESEKESE. +2349014572744ISENA RE:-EBAMI WA EWE LAPALAPA FUNFUN ATI PUPA, EWE ABAMOD...
21/05/2024

ISE EYONU AwON AGBA, TI ALE FIRI OWO LESEKESE. +2349014572744

ISENA RE:-
EBAMI WA EWE LAPALAPA FUNFUN ATI PUPA, EWE ABAMODA IYEKIYE OWO NAIRA ((ANY AMOUNT)), ODIDI ATARE KAN, OYIN GIDI.
Call me ((09014572744))
SISE RE:-
AO FI OWO YI TELE IKOKO AO FI ATARE SI AO KO AWON EROJA TOKU SI, AO JO PAPO AO DA SINU OYIN AO MA FI IKA ARIN LA NI ARO KUTUNKUN, IYALAYA OWO LA MAA RI ,,O SURE BAJE..

IKILOPATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare

FUN IBEERE TIONI ITUMON ATI FUN IRANLOWO ONAABAYO SI GBOGBO ISORO AYERE CALL OR WHATSAPP TIOBA NIGBAGBO +2349014572744

Address

Oke Agbo
Ijebu Igbo
120105

Opening Hours

Monday 00:00 - 23:00
Tuesday 00:00 - 23:30
Wednesday 00:00 - 23:30
Thursday 00:00 - 23:30
Friday 00:00 - 23:30
Saturday 00:00 - 23:30
Sunday 00:00 - 23:30

Telephone

+2349014572744

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when The most powerful herbalist native doctor posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Contact The Practice

Send a message to The most powerful herbalist native doctor:

Shortcuts

Share