Iwosan Eda Lona Ewe Ati Egbo

Iwosan Eda Lona Ewe Ati Egbo YIWA FUNKI AGBARA WANI IMORAN LORI EWE ATI EGBO FUN AWON AISAN TOBASE OMOEDA LORISIRISI, OMISHA 08116270933 /07034254793

11/02/2026
HAPPY BIRTHDAY TO ME IN ADVANCE  THIS FEBRUARY 27 IS MY BIRTHDAY DAY           hi chief elemosho apero iregun ijesha osu...
11/02/2026

HAPPY BIRTHDAY TO ME IN ADVANCE
THIS FEBRUARY 27 IS MY BIRTHDAY DAY hi chief elemosho apero iregun ijesha osun state eledumare will bless my income Golding new age in advance to me

Ewe afeloruEPO oboImiojoAtare odidid kanEru Alamo.SISE re ....Ama gun awon eronja yi po ninu odo taba ti gun dada to kun...
02/02/2026

Ewe afeloru
EPO obo
Imiojo
Atare odidid kan
Eru Alamo.

SISE re ....Ama gun awon eronja yi po ninu odo taba ti gun dada to kuna... Awa lowa sa si ibiti ategun ati ma fe si dada.. toba tigbe.. ama fin ni turari ni ooo...
Turari toma le ogun okuta ninu ile tabi shop eyan ni oo.. note kosi igba ta le fin sugbon arawa gbodo wa ni mimo

ORI ELEDE OJOOIYO ABO MEJIEWE SAWEREPEPE TUTUOGEDE OMINI 21OBI ABATA OLOJU MERIN 21EPO IGO KAN OYIN IGO KAN  SISE RE. AO...
27/01/2026

ORI ELEDE OJOO
IYO ABO MEJI
EWE SAWEREPEPE TUTU
OGEDE OMINI 21
OBI ABATA OLOJU MERIN 21
EPO IGO KAN OYIN IGO KAN SISE RE.
AO GBELE SI ENU ONA ILE ITAJA WA ..
AKOKO DA IYO ABOKAN SI INU RE..AKO EWE SAWEREPEPE DIE SI AWA GBE ORI ELEDE YEN LE.. AWA DA IYO TOKU LE LORI ADA OBI LE LORI ADA OGEDE YEN NA LE LORI.. AWA TU OYIN ATI EPO YEN LE LORI..AWA KO EWE SAWEREPEPE TOKU LE LORI.. AWA DA IYEPE PO.. AKIYESI AJEKI ORI ELEDE YEN KOJU SI INU SHOP WA NI OOO... ...AWORO ARIMOLE AJE NI.. OSISE DADA .

27/01/2026

Loni ojo isegun gbogbo wa lama segun ota wa ooo

.EJE KI AWA AGBON KAN TONI OMI NINU...ERAN MALU EKIRI META..OWO TUNTUN BI 1K TABI 500SISE RE NI YI OO..AMA JO OMI INU AG...
27/01/2026

.EJE KI AWA AGBON KAN TONI OMI NINU...ERAN MALU EKIRI META..OWO TUNTUN BI 1K TABI 500
SISE RE NI YI OO..
AMA JO OMI INU AGBON YEN SI INU IKOKO ASEJE YEN..AWA KO ERAN EKIRI META YEN SI AWA GBE KANA TI OBA JINA TAN TI OMI TI RE TIGBE MO ERAN YEN.. AWA SO SI ORI OSUKA KAN..AWA SA INA SI OWO TUNTUN YEN AWA JUSI INU KOKO ASE JE YEN TOBA TI JONA TAN AWA FI OWO HAND.. PO ERU OWO YEN MO ERAN YEN AWA SE ADURA SI KATO KOJE..TABA JETAN AMU OMI AYE LE LORI...IDAJI KUTU TABI AWOLE SUN NI AMAHUN SE ISE YI.... ISE TO DAJU PUPO NI FUN AWON ONI SE OWO TABI AWON TOHUN TA OJA..ASEJE AWORO NI..

..ASEJE ASIRI BIBO TODAJU..Epo jeboAta ijosi Ejeki alo mejeji po ko kuna dadaKa lowa kindirin molu ka gesi ona mesansise...
25/01/2026

..ASEJE ASIRI BIBO TODAJU..
Epo jebo
Ata ijosi
Ejeki alo mejeji po ko kuna dada
Ka lowa kindirin molu ka gesi ona mesansise re.
Ako kindirin yen si inu isasun aseje awa da epo jebo yen si lori awa fi epo si afi iyosi.. note agbodo fi omi si oo.. awa gbe kana lari iseju marun ati jina kaso si ori osuka kawa koje.. mofi eledumare bura..aseje asiri bibo ni..eje je lemata larin ose...

Ewe aje Ewe sawerepepeEwe papansaAwa lo pomo ata ijosi mesan Afi se Edo molu mesan je lepo niyo(Aseje eyonu) ...   ..
24/01/2026

Ewe aje
Ewe sawerepepe
Ewe papansa
Awa lo pomo ata ijosi mesan
Afi se Edo molu mesan je lepo niyo
(Aseje eyonu) ... ..

23/01/2026

My festival things nani ooo.. isese agbewa ooo.
23/01/2026

My festival things nani ooo.. isese agbewa ooo.

Address

Iregun Area Along Osogbo Ilesha Road Osun State 07034254793 Or 08116270933
Ilesha

Telephone

+2347034254793

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Iwosan Eda Lona Ewe Ati Egbo posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share

Category