25/03/2026
ASIRI IRAWO INA TONTAN YANRAN(ARIES ) ♈️...part two
AWON OMO ARIES ♈️ NI AWON TIABI NI (March 21 - April 19)...
ARIES ♈️ ( THE WARIOR, THE PROTECTOR & DEFENSIVE CREATURE, THE FEARLESS LEADER,THE COURAGEOUS, THE SPEAKER OF THE TRUTH WITHOUT FEAR,CREATURE WITH THE SPIRIT OF AGGRESSION & FORCE ).....
Olu dabobo(defensive people) niwon...tori security won lagbara pupo...ninu iseda irawo toma ndabo bo awon family ati ololufe re ni aries wa....
Asiwaju niwon ninu ile...koda kojepe ohun ni last born...huhmm(Akehinde gba egbon lenwo yen)...
Tori ohun loma pada pase ile (ruler of the house )
Olupile nkan niwon je (the founder or creator of things)...won ni agbara ati enu(gift and talent to begin new things) lati da nkan kale ni nkan ti eniyan kan koti seri....(they are Cardinal sign)
Aries ♈️ je eda kan ti ero erisirisi (ideas) ama wasi won lokan tori re ni won fi ni ikapa lati da nkan sile...olupile(the creator )
Sugbon ero opolopo won okin nduro si ojukan rara, osima nsoro funwon lati duro lori ise kan tabi isesi kan ,gbogbo nkan loma nwuwon se tori re ni won nkin fi ri aseyori se lasiko....
ogbon inu won po gan ,wonde mu sasa (smart in action ),okun ati agbara (energy and strength) wa funwon...
Ninu eda toma nsoro pelu igboya ,won okin beru atiso otito tabi soro si eniyan (self expression in speaking and they don't hide the truth...the truth most be told) 😁
Ilakayi poju fun opolopo omo aries(bold and wise) opolopo won ja fafa(very active,smart and sensitive)...ogboju ati igboya (courageous and brave) wa fun opolopo won ....
Opolopo won je oninu rere toni okan kan niwon fi ma nba eniyan se (loyal )...
irawo yi lo nje oba ogun(iron) tori iwa ati isesi won le pupo, eniyan lile niwon, wonsi buru gan....
Iwasi aiye ati isesi won jo ti ogun ile yoruba tori re ni afi npe orisa awon irawo aries ni iseda ogun (iron)...
Irawo yi wa ninu irawo Toni igboya ju ninu gbogbo irawo mejila tiani (the boldest and most courageous among the 12 zodiac signs)....
Aries je irawo toni agbara tie (energy)...Mars ni planet to ndari irawo won leyi totun lekun agbara aries ,Mars loso aries di eniyan to ni opolopo okun ati agbara (very energetic)...
ETC....
Eje Kin Nda Owo(✍️) Duro Bayen Na....
WRITER:- OBA IRAWO✍️✍️ ✍️
WATCH OUT FOR NEXT PART
ASIRI PO LABE IRAWO KOKAN TIKOSE SOTAN, TORIRE LOFISE PATAKI KI ENIKOKAN MA ASIRI IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE,KOLE MA BI OHUNSE MA RIN IRIN AJO AIYE RE..
MOSE IBA AGBA 🙌
FUN IBERE TABI IWADI NIPA IRAWO ATI AKOSEJAIYE RE... MESSAGE ME ON WHATSAPP WITH THE NUMBER ON MY PROFILE