14/04/2026
AGBARA OLORUN SIWA OO, INKAN KEKERE TI ELOMI YOSE RE TI KOSI NI JIYA MON LAYE , OLORUN MA TOBI OOO
gbogbo irawo pata ni asiri yi ba sise ijile nla ni asiri yi, bi eyan ba se asiri yi odi dandan ki onitohun bo ninu ide patapata ti ona re yosi le kedere , asiri nla ni asiri yi, aro kutu lo se asiri yi Kato soro si enikeni,
ao bu rice die si òwó ✋ otun wa pelu iyo na die si òwó ✋ otun wa, ao wa duro si enu ona YARA wa, ao wa gbadura si bayi wipe , gbogbo ide ti aye Fi de aye mi ati ise mi tiko ko je ki ki ri ona lo ki ide na ja danu lati oni lo ooo , ki bere sini ri Owo na lati oni lo ,kiri bati se ki ri ona gbe gba ninu ose yi, ÀMÌN ase , ao wa lo fon rice ati iyo na si waju ita wa, walahi lati IJO yen lo ao tun jiya mon laye ooo gbogbo inkan wa ni yoma lo Dede lati IJO yen lo , asiri awon baba wa ni asiri yi.
IKILO PATAKI
tio bafe ki ise yii je fun o dada koko bami share ise yii si opolopo group kosi fi comment re se adura tio bawu o funmi nitori anfani elomi ni oro gbogbo yio di ayo ninu odun yii lase edumare