29/02/2024
Awon egbe irawo omi, won pin si meta: CANCER(ALAKAN), SCORPION(AKEKE), PISCES ( EJA)...
Awon ti won bamu adamo or irawo Omi wa si aye, ma saba je eniyan jeeje, won kin tete binu, sugbon won ma saba yan di ninu iwa won, won ma saba ma nro ara won pin nigba ti adanwo ba de siwon, awon egbe won si saba ma dawon pupo lori iriajo aye won lata ri, ti won nba rin irin tiko ba, eleda won lara mu,adua won si tete nma gba, ti won nba se adua sinu omi tabi hantu, tira, won o tete kona lo pelu Sara, toba won lara mu...
Awon elegbe won si feran anu pupo, sugbon won ki rira njan dudu....
AWON OMO OMI
Awon ISEDA OMI ma ri awon egbe won dada loju orun tabi loju ran pelu wipe ti won RI ona ti o ye karin pelu ILANA to to....
Awon omo omi kan wa to je PE ADUA fun eleda won ATI Sara to ye NI awon egbe won nfe, nijo ti ba ti bere, ijo na ni ayipada tide saye won...
Awon omo omi kan wa toje pe, kiwon jina si nkan ewo won NI, awon egbe won yo fi fara han won KIAKIA, Koda tiwon yosi mase ipade ninu aye... Pelu awon majemu ti eledua fi seda won...
Awon omo omi kan wa ti afun ni ase ti nbe Lara won, toje PE, TI won ba mojuto ASE yi( NI ori ni, abiya NI, oju ara e.t.c) TI won bape ojo ori kan ninu aye, awon egbe won yo fi ara han won dada, TI nsi sele ninu pelu research todaju, TI AO si ba be...
By AR-RAZAQIY INTERNATIONAL
WhatsApp number or call
08105428760
By AR-RAZAQIY....