Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ Spiritual Consultation And Solution

30/07/2026

★ ★

Njẹ gbogbo eda eniyan nii oun rántí àwọn ala rẹ bi? moti soro koja lori okunfa gbogbagbe ala

Njẹ iwọ mọ pé ala réré kii ùn tètè wá síi imuse tii akoba tẹra mọ adua ati igbinyanju moti soro koja lori eleyi na

Njẹ iwọ mọ pé lati Agogo méjìlá ọsán (12:00pm) nii ala buruku tii abala nii oru mójú tii ùn wa síi imuse

Njẹ iwọ ti ẹ rán ti wípé lati ọjọ ti wan ti bi ẹ iwọ kii la àlà rere jekin so fún ẹ ai lala réré ko túmọ sí wípé oole se oríire láyé sati mójú tó ọrọ ayé rẹ kòsí ìṣòro tí koni ona abayo.

Iwọ ti òun fi òjòó jumọ lalá rere Njẹ lati ọjọ ti wan tin sọfún e wipe òòrè nbọ njẹ òòrè yi tide

Hummm ọmọ ìyá mi scam ni ọba Lola mójú tó ọrọ ayé ara rẹ ni, bi obaun fi òjòó jumọ lala réré lai gbé ìgbésẹ kankan ojukanna ni oma wà

★ ★
👇
Bíi obalala pe oun ríi ẹyin ọpẹ nii gbogbo igba loju ala.
Ìtumọ:- wa ríi nkan rere nii àkókò yẹn madake lori oro aye e.

Bíi okùnrin bá lala pe oun wo aṣọ 👘 obìnrin lójú ala
Ìtumọ:- iru enibe yóò Pàdánù ogo re sí ọwọ elòmíràn

Bíi obalala pe eyin 🦷 ẹnu rẹ yóò loju ala
Itumo:- eniti ogbè ọkan le gege bíi alaanu yóò ku tabi kii ofi ee silẹ nii igba àìrotele mura dada

Bíi obalala pe oun wo mirror loju ala
Itumo:- wa nii ibasepe pẹlu awọn eyan réré tiyo fa ẹ gunke

Bíi obalala pe 🥚ẹyin Jabo nii ọwọ rẹ lójú ala.
Itumo:- gbàdúrà kii nkan rere mase bọ lọwọ rẹ.

Bíi obalala pe oun ríi osupa 🌙 loju ala nii gbogbo igba
Itumo:- wa ríi nkan rere airotẹlẹ tẹra mọ adua masi ro ala yi fun eniyan.

Bíi obalala pe oun fa siga 🚬 loju ala tii kii ùn se pe oùn fa siga loju ayé.
Itumo:- nkan ti oolero ni aburú asele sie mura dada.

Bíi obalala pe òun jẹ àkara ati 🍞 bread loju ala.
Itumo:- leyin inira nkan rere nbọ fún e sugban mura ki ota mayi ala rere si idakeji fune.

Bíi obalala pe oun jẹ àkara lasan loju ala
Itumo:- ifaseyin nii mura síi adua daada

Bíi obalala wipe won fún ee nii owó àjọ tabi won na ee ni owo loju agbo loju ala.
Itumo:- gbese tabi oda owó 💰 yo sele siẹ mura dada.

Bíi obalala pe oun wẹ ninu odo 🏊‍♀️nii gbogbo igba loju ala tii ọ jẹ pé iwọ nikan ṣoṣo nii
Ìtumọ:- gbàdúrà daada nitori pe idaamu ni.

Bíi obalala pe owa ninu Igbo aginjù tabi owa nínú òkùnkùn loju ala nii gbogbo igba
Itumo:- idamu aye raye nii mura si oro aye re.

Bíi obalala pe oun ríi tomato🍅 nii oju ala yala owa ninu motor tabi won fún ee
Itumo:- wa ríi oore tii ofi ojú jọ ibí.

Bíi obalala pe oun ta oja loju ala nii gbogbo igba tii kii ùn se pe oun ta oja yi loju ayé
Itumo:- ọlọhun fẹ lo ee gẹgẹ bíi oludari nii aayékan sugbon idamu yóò dìde si e nibe gbeyin.

Bíi obalala pe oun jẹun pẹlu awọn tii oju ee lọ loju ala.
Itumo:- wa pada dii àsiwaju nii ibi kan

Bíi obalala pe oun jẹun pẹlu awọn ọrẹ rẹ nii oju ala
Itumo:- wa pada di asiwaju nii aayékan sugban awan ota maùn sasi abẹ iru awọn ala yi latifi ara pamó jẹ eniyan ni iya.

Bíi obalala pe oun ríi ade👑nii ori ee loju ala.
Itumo:- wa pada di olori tabi eni apesin nii aayékan.

Bíi obalala pe owa lori esin🏇 loju ala
Itumo:- laipe wa di ẹni apesin láwùjọ.

Bíi obalala pe oun ríi awọn ore (friends) ee nii gbogbo igba
Itumo:- ikólọ rẹ ùn pada bọ ṣugbọn oni lati tẹra mọ adua.

Bíi obalala pe oun ri Ex re loju ala nii gbogbo igba
Itumo:- Onitoun ùn rántí ee bẹ sí ni nkankan sima pada dayin papọ

Oluwa so imoran ota di ofo lori gbogbo eyin ololufe mi amin.

Call/WhatsAp
+2349035004212.
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

30/07/2026

★ ★

Ọpọlọpọ awọn òbí níí ko mọ pe aini àkíyèsí lori ọmọ tii ohun bíi níí okunfa iṣoro sínú aiye ọmọ rẹ.

Kii ùn ṣee gbogbo iṣoro tabi wahala tii a ùn dojukọ bayii níí owá lati ọwọ ọta bẹ sini kii ùn se gbogbo igba naa nii ogun ìdílé ùn dáwà láàmú nje iwọ mọ pé ọwọ àwọn òbí ee níí wàhálà yìí ti waye gege bíi àpẹẹrẹ;

K'odara kii ama Ju kainkain tii afi wẹ ẹjẹ kuro lára ọmọ tuntun ni ina

Eleyi ma ùn fa ikorira sinu aiye ọmọ níí ọjọ ọla Ni.

K'odara kii ama gbé planceta ọmọ wa fún èyán kan sá nítorí pé bíi wọn bá fi cook planceta yi fún ìyá ọmọ jẹ

*Eleyi le fa iku aitojo fún ìyá ọmọ

*Bii ọmọ bá fii mu ọmu leyin ti iya ti jẹ planceta ọmọ rẹ iṣoro níí iru ọmọ bayii yóò fii lo gbogbo ọjọ aiye rẹ̀.

K'odara kii ama da omi iwẹ ọmọ sí ojú t**i tabi inu gulthar
Gbogbo ọmọ tii wọn ba ùn se eleyìí fún.

*Èyí ama fa ikorira sinu aiye wọn

*Iru awọn iseda bayii kii ùn ni akojọ

*Iru iseda bayii kii ùn ni ifokanbale ati ibujoko ninu ìgbéyàwó wọn.

K'odara kii abiyamo máa ya Irun síi ọmọ ìkókó níí ara agaga ọmọ ti koti pé 41 days

*Eyi ki ùn jeki irawọ ọmọ wúlò fún ni ọjọ ọla

*Asedanu yóò ma ṣẹlẹ sí irú àwọn om báyìí

*Wọn kii ùn saba níí itelorun pelu ọkọ tàbí aya wọn.

K'odara kii abiyamo ma gba awọn eyan láyé láti máa gba awọn ọmọ wan lórí nítorí pé

*Eyi má ùn fa ògo aiye ẹda sẹyìn

*Iru àwọn báyìí kii ùn ga to àwọn akẹgbẹ wọn níí ọjọ ọla

*Gbese jíjẹ níí gbogbo igba níí iru nkan bayii ùn fa

K'odara kii ajeki awọn eyan máa gùn àwọn ọmọ wa bíi esin 🐎 agaga àwọn ọmọ kékèké

*Èyí kii ùn jeki ọmọ tètè ri ògo aiye lo

*Eyii ma ùn fa kii ọmọ siyan níí ọjọ ọla.

*Èdè aiyede yóò ma ṣẹlẹ ninu ìgbéyàwó ee niii ọjọ ọla.

K'odara kii abiyamo máa fii aṣọ ẹjẹ tii ofi bíi ọmọ tafala nitori pe won ma ùn ló awọn aṣọ yìí fún àṣírí bibo

Njẹ iwọ mọ pé gbogbo owó tí oyẹ ki ọmọ ee níí eniti ose iṣẹ yii níí yoo máa ni iru owó bayii

Níí gbogbo igbati oba mu ọmọ rẹ lọsí saloon lati lọ ṣe Irun ori Re gbiyanju kii osa gbogbo irun ori ọmọ rẹ ti ojà sile nítorí pé awon amokun se'ka ma ùn fii gba ogo aiye ọmọ, eyi sile fa wàhálà sinu aiye ọmọ na níí ọjọ ọla.

Máṣe gba awọn ọmọ rẹ obìnrin láàyè láti máa Pin bàtà 🥿👠 wọ pẹlu awọn ọrẹ wọn níí igba èwe gbogbo ọmọ ti oba ùn se eleyii odidandan kii ofi ori kò ogún ológun.

Máṣe gba ọmọ rẹ ọkunrin láàyè láti máa Pin aṣọ🧥👚👖 ati fila 🧢 wọ pẹlu awọn ọrẹ wọn nítorí pé wọn má ùn fi eleyi Change kádàrá ati ògo ọjọ ọla ẹda

Idaamu konije tiwa o amin.

Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/WhatsApp
+2349035004212.
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

28/07/2026

★ ★ {PART 9}

ẸGBẸ́ orun je ẹgbẹ́ ti eniyan yan lati ORUN wa Orisirisi egbe ni o si wa

Gbogbo awan ẸGBẸ́ wonyi ni won ni èèwò, Won si ni ohun jije tabi eso ti won feran, ẸGBẸ́ orun pọ lorisirisi gege bi mo se so saaju.. Ati okunrin, ati obinrin lo leni ẸGBẸ́ orun. A o se alaye egbe yii leyo KỌỌKAN.

1. *EMERE OMI*
👇
Awon wonyi, ọmọ omi niwon. Inu omi ni won ti nse ipade. Won ni agbara pupo ju ẹgbẹ́ toku lo. Won ma ùn rewa lobinrin. Promise and fail maa ndawon laamu.

Ẹgbẹ́ omi lo poju ninu awon obinrin, Ọkọ ti ko ba mon won kole fe won si ile, Awon eda timowiyi won po ninun irawo omi ati irawo ina. Eyi ti ọkọ orun bati da majẹmu fun kiiri ibujoko ọkọ. Beni okunrin won na maun ri isoro ki obinrin maa fiwon sile. Oropo nibe

*2. EMERE OFURUFU*
👇
Awon wonyi wa ni oju ofurufu(agbede meji aye ati orun ni won ti ma ùn se ipade.. Awon wonyi ni agbara lọpọlọpọ. Awon ti won ba ni egbe yii, yio ma ri ara won loju ofurufu won po ninun irawo Afẹ́fẹ́. Ati irawo ina. Ẹgbẹ́ yi ma un tete gbe eniyan dide.

3 *EMERE OLOGEDE*:
👇
Inu ọgẹdẹ ni won ti nse ipade tiwon. Awon wonyii buru jai. Emi eniyan kii jowon loju. Beeni, won kii ni emi idariji. Obinrin ọmọ elegbe yi won ki pe sunkun. Besini won buru pupoju.

4. *EMERE ORI AKITAN ALAKISA*.
👇
Awon wonyi, ori akitan ni won ti nse ipade. Alakisa ni won. Bi DANGOTE ba fe won sile, yio pada di edun arinle ni ojo aye re..Gbogbo okunrin to ba ni ibalopo pelu emere alakisa, yio pada di olosi ni ojo aye re. Opo ninun yara irawo Afefe ati ile irawo iyepe oro po nibe.

*5.EMERE ORITA META*
👇
Orita meta ni ile won. Ibe naa ni won ti nse ipade Awon edayi won buru gan. Won ose baja won osi see base awada won ma un binun sodi ni, obinrin won maun sadede kanra mon yan won ki rerin siyan. Won si maun nife ọkọ won. Won kii fe kiwon bawon fe ọkọ awon eni badan won oku leleja taa

*6..EGBE ASHIPA*
👇
Awon ọmọ ashipa kii kawe, won kii ko ise. Ti eba ranwon lọ si ile iwe, o fi owo re sofo ni. (U just waist ur money) Won kii gbo tenu obi. Iran Ashipa je iran jagunjagun.. isẹ ti ọpọ àwọn ọmọ ashipa maun yan láàyò jẹ isẹ lile gẹgẹ bí soldier, navy, airforce, area boys, thugs, millitant, armed robbers, terrorist, dangerous herdsmen etc..

7.EGBE ALARAGBO
8.EGBE IROKO
9. IRANSE AJE(WEALTH)..

Àlàyé nbọ lori awọn mẹtẹta yi ninu next post

*DIE LARA ISORO ATI IDAMU TI ELEGBE OMO MAUN RI NILE AYE*

1.Majemu iku ojiji
2.isoro oko orun tabi aya orun
3.Amubo oko ati aya
4.Iyaagan(Barreness)
5.Bibi abiku
6.ijakule

6. Elomiran ninu won ko ni ri ọkọ tabi aya fe ni ọjọ aye re

7.Elomiran yio maa kuro nile oko kan bo si omiran. Obinrin miran ti fe oko meta, merin tòótọ laimo wípé ẹgbẹ lóun daamu ìrìn àjò ayé òun

8.awon elomii kii ni ibujoko dojo ale

9.. awọn Elomiran yio maa fi ise abe(operation bimo)

10.awon Elomiran yio maa je gbese

11.awon Elomiran yio kowo pamo sile, owo(money) naa yio poora

12. Awọn Elomiran awon elegbe re yio maa daran si lorun

13. Awon miran kii ni alaafia. Gbogbo ojo aye won ni won yio fi se aisan.

14 Siso owo nu(money) tabi ohun ini miran(valuable things)

15. Pupo ninu elegbe omo ni isoro 1 to15 yii maa nba wo inu sareeeee

*KINI IDI TI AWON ELEGBE OMO FI MAÙN RI IDAMU ATI ISORO NINU AYE.*

Ìdí nì wipe Orisirisi majemu ni wón ti da ninu ẹgbẹ́ naa ki won to wa saye. Nigba ti won de ile aye tan, ọpọ nínú wọn jẹ eewọ, ọpọ nínú wọn dalẹ (betray) ọdàlẹ ba ile ku, eni ba dale, yio ba ile lo.

Oògùn, ose, aseje, gbere, hantu, eto adua kii ran ẹgbẹ́ orun ooo.. Bi eniyan ba fi se oogun, awọn ègbé yii ni yio ba gbogbo re je..

Abiku so oloogun deke loro awon elegbe omo Awon emere kekeeke, eyi ti e fi eran, eja, akara etc tan wonu egbe ninu aye yii, ni e le fi oogun yo kuro.

Egbe orun buru jai. Wọn kìí yọ wọn kuro ninu ẹgbẹ Bi eniyan ba gbiyanju lati yo won kuro ninu egbe, won yio fi iya nla je onitohun..

Ọpọlọpọ woli, alfa, Babalawo ni emere orun ti so di ero orun toriwipe wan dawole oun ti agbara wan koka latise.

Opolopolo muslim ati Christian lo ti gun gbogbo ori oke aye yii. Bi won se nkuro lori oke ikoyi, ni won se nbosi ori oke Ọlọhun kole, Elomiran ti gbawegbawe, o ti ru kan eegun..

Elomiran ti gbadura gbadura. Awon miran tun maa nfi ede fo, sibe sibe nko? pabo naa ni gbogbo re njasi...

Ọmọ ìyá mí ma waist àsìkò rẹ mọ lọse àwárí ará rẹ láti mọ iru ẹda ti ojẹ àti gbogbo òun tó romo ìrìn àjò ayé rẹ.

Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/Whatsapp
+2349035004212.
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

25/07/2026

★ ★

(SNAKE)

Bi ose bami share post yi fun ànfàní ọpọ ènìyàn Ọrọ aye rẹ koni dojuru amin.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo ni adugbo re,
Itumo:- awon ota adugbo won un bínú òòrè olohun lara rẹ múra dada.

-Ti eniyan ba lala wipe ohunri ejo ninu omi tabi odo (river)
Itumo:- enina yio ri iranlowo lati ọdọ àwọn ènìyàn.

Ti eniyan ba lala wipe ohun nsin ejo itumo:- enina yio di alagbara laye.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri iboho ejo,
Itumo:- enina yio ri òòrè lati ọwọ ota.

Ti eniyan ba lala wipe ohun fi iboho ejo we ara re,
Itumo:-ota re yio fi ara han, enina yio da ota re mo.

Ti eniyan ba lala wipe ohun pa ejo eje re wa yi eniyan lọwọ tabi ẹjẹ jade Lara ejo yi,
Itumo:- enina yio bori ota. isegun ni.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo toun tu oro jade lenu,
Itumo:- eniyan nla ni ota enina, ota re lagbara juẹlọ.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo ti won ti pasi oju popo (road side) tabi adugbo,
Itumo:-ija ni ki enina sora daada ki o ma dasi nkan ti kokan ẹ.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo kekere,
Itumo:-won ma lo omo kekere gegebi ota fun ẹ.

Ti eniyan ba lala wipe ohun se ode (Hunter) ejo,
Itumo:- ota ko mo irin ajo eniyan, eniyan nmu ota re sere.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo dudu,
Itumo:- enina ni ọta to lagbara juu lo.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo funfun,
Itumo:-enina ni ota ti ko lagbara juu lo.

Ti eniyan ba lala wipe ejo n ba ohun sọrọ loju ala tosi je ọrọ to dara tosi ni itumo gidi,
Itumo:-wa ri òòrè lati ọwọ ọta rẹ.

Sugbon ti eniyan ba lala wipe ejo nba ohun soro tikodara tabi ọrọ ti ko ni itumo,
Itumo:-enina yio ri inira lati ọwọ ota re.

Ti eniyan ba lala wipe ohun di ejo
Itumo:- ẹṣin tabi ipò ti eniyan wa ko te eniyan lorun. Awan ọmọ elegbe kan na situn wa ti wan maun la ala yi.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo toun jeun Lori tabili(table)
Itumo:- ipinya nbọ larin iwọ ati awọn ọrẹ rẹ, torí wipe awọn ọrẹ rẹ yo pada dalẹ (betray) rẹ.

Ti eniyan ba lala wipe ohun ri ejo ni ile asale(dessert) ile ti o tejulo
Itumo:- òun múra ìrìn àjò (travel) kan sugbon awon olè ( harmrober) má dà ẹ lónà ni ìrìn àjò (travel) yẹn.

Ti alaboyun ba lala ri ejo
Itumo:- alagbara ni ọmọ ti yoo bi tabi kobi ọmọ okunrin.


Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/WhatsApp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

23/07/2026

★ ★

BAMI SHARE POST YI FUN ANFAANI OPO ENIYAN OGUN IDAAMU KONIJE TIE AMIN.

TI ẸLÒMÍRÀN BA LALA WIPE OUN JEUN LOJU ORUN YIO TUN JI YIO BA EPO NI ỌWỌ RE ATI ẸNU

AWON ẸLẸ́YE NI WON GBE IRU ENI BE LOSI INUN IPADE LATI NUN LOUNJE NI OJU OORUN.

TI ELOMIRAN BARI IRU APERE BAYI AGBA ILE IWOSAN (HOSPITAL) LO. TI WON BATILE FUN NI ABERE WAHALA TIDE

TI ELOMIRAN BA LALA WIPE ESE UN DUN OUN LOJU ALA TOBA JI SAYE ESE NA YIO MADUN ENI NAA

TI ENI YAN KOBA MOJU TO RARE GBOGBO OJO AIYE RE ESE YEN NI YIO MANA OWO SI.

TI ELOMIRAN BA LALA WIPE WAN NA OUN NI EGBA NI OJU OORUN TOBAJI SAYE ABA OJU APA EGBA NI GBOGBO ARA E.

OJU ORUN NI WON TI BA GBOGBO IGBIYANJU ADUA ATI OOGUN TI ẸLÒMÍRÀN SE JẸ TI ỌRỌ RE FI DARU DE IBITI TODE LONI AINI AKAKUN LORI ORO AYE E LOBATI OPOLOPO JE TI ORO AYE E KOFI NI ATUN SE MO

OLOHUN NIFE AWAN EDA E TOBEE GE IDI NIYI TOFI FI ALA LILA SE ATONA IRIN AJO AYE WA SUGBAN BI ALA LILA SEJE ATONA AYE EDA TO KONI ITUMO LOJU ELOMIRAN IDI NIYI TI ELOMIRAN FIKO SINU ISORO AYE RAYE

Ona meji nii ala ma ùn gbawa bẹ sini bíi eda koba mojuto oro aye e oseese kii ala buruku semo lara

Ni otito kii se gbogbo ala loni itumo tori wipe Ohun ti elomi baro sun yio pada fi lala. Abi owo film sun.

Alalila ma ùn waye lati ọwọ awọn amokunseka lati ba aiye awon eniyan je

Ala lila maun wa lati owo oba Adeda. Lori ohun tofe sele si eda.
Ala lila maun sele si eda lati salaye irin ajo aye eniyan fun nipa bi ojo ola e aseri

Gẹgẹ bí àpẹẹrẹ;

* nii àkókò tii ẹlòmíràn ma nii appointment pẹlu eniti yóò sọ di olorire nii awọn ala íbalopo oju orun maun waye leyin tii obaji saye tan odidandan kii oba s***m nii arare.

Eleyi ni aun peni ogun awan Arogo siwaju ologo. Wan ti ta ofa ogun ifaseyin ati Amunbo oore sinu aye iru eda be.

*Oúnjẹ oju orun nii gbogbo igba

*Egungun ma ùn le ẹlòmíràn nii oju orun nii gbogbo igba

Mogbadura fún gbogbo wa pé alaburuku koni se mowa lara mon amin sugban amin nikan ko wa mojuto oro aye e ni

Iwo eda toka post mi tosi gbo ohun mi. Jekin so kini kan fun e loni
Orire kije ki won ri ohun se.
Besini Aseyori na ki gba ki won ri ohun se. Iwo ni oni gba Fun awon ika eniyan

Iseda elomiran kogbodo ko ori si ibiti oorun (sun) tiun yo iseda elomiran kogbodo ko ori si ibiti oorun (Sun) nwo si nje gbogbo awan nkan wan yi ni iwo mon?

Elomi awan ẹgbẹ́ ti Wan un se Alakoso irin ajo aye re ni won un binun si

Elomi ibi ti Awon ALUJANUN ko ori si ibe ni ohun na un ko ori si Kobadara ki otete se awari ara e ki idaamu todi best friend e

Elomi awan obi re lofa wahala sinun Aiye re.

Elomi agbole baba ni wan ti connect CCTV mo lara ti wan fiun monitor aye

Mofe ki amo wipe akoko ti abi omo eniyan si aye ose pataki owuro ni osan ni abi ale nje iwo mo wipe akoko yi ni awan eni ibi tilo against e ti oofi se aseyori

MOFE KI ALOMO WIPE IGBESI AIYE EDA ATI ISORO TI ỌMỌ ENI YAN NKOJU OGUN AYE EDA KO NIRA LATI SE BI EDA BATI PADE OLODODO ENIYAN.

AWA NIKI EJE KALA OJU WA KI AMALO KOSI OWO AWAN ONI JIBITI EDA NI OTITO NI AWAN YORUBA SOWIPE INU YARA IRO LATIUN PADE ODODO ITUMO OROYI NI WIPE IBITI ATIUN DAAMU KAKIRI NANI AOTI PADE ODODO TI AOBA RELENT.

OLOHUN BAMI DUN GBOGBO EYIN OLOLUFE MI NINUN KI ISORO AYE GBOGBO YIN DI OUN IGBAGBE.

*★ÀLÁ ÀTI ÌTUMÒ★*

Bíi obalala pe Oun ko iyepe loju ala nii gbogbo igba
Itumo:- laipe wa kò ọrọ ati ọla jọ tẹra mọ adua

Bíi obalala pe oun ríi àgbo fúnfún tabi won fún ee nii àgbo fúnfún loju ala
Itumo:- laipe wọn yóò dáa ìnáwó nla sí e lọrùn tẹra mọ adua.

Bíi obalala pe oun ri àbo pẹpẹyẹ 🦆 loju ala
Ìtumọ:- adawole iru enibe yóò yori síi réré

Ṣugbọn bíi ibaje akọ pẹpẹyẹ 🦆 nii
Adawole iru enibe yóò fé mu inira daani

Bíi obalala pe owa ninu oko Isu nii oju ala
Itumo:- wa nii akojọ oore tii o pọ gan

Bíi obalala pe oun ri osupa 🌙 nii oju ala
Itumo:- wa ríi ikan ayọ laipe tẹra Mọ adua

Bíi obalala wipe won fún ee nii ☂️ umbrella ☂️nii oju ala
Itumo:- wa ríi eniti yóò bo ee nii asiri ninu ìṣòro tẹra mọ adua

Bíi obalala pe owa ninu ọkọ ojú omi🚣🏿‍♀️ .
Itumo:- gbàdúrà kii omase ti arare bonu ìṣòro

Bíi obalala pe o fii iwọ gbé ẹja 🎣loju ala
Itumo:- laipe nkan tii oun wa yóò pada tẹ ẹ lọwọ tẹra mọ adua

Bíi obalala pe oun ya igbẹ si ara laarin awọn ọpọlọpọ eniyan
Itumo:- hummm mura kii omaba ṣẹsin

Bíi obalala pe oga ju bíi òsé wa lo loju ala.
Itumo:- àìsàn tii yo mú ikú daani nii tẹra mọ adua

Bíi obalala pe idin🪱 ùn jade kuro nii arare loju ala.
Itumo:- àìsàn yóò jina sí ee kunfun adua

Bíi obalala pe owa ni ìhoho nii ita gbangba
Ìtumọ:- ṣọra kii omaba dii ẹni ẹyin tàbí kii àṣírí ee tu.

Bíi obalala pe oun sá ẹyin ọpẹ loju alá tabi oun sá Olu
Itumo:- wa ríi nkan ìdùnnú tii yóò mú owó 💰 daani.

Bíi obalala pe oun sá oko loju ala nii gbogbo igba
Ìtumọ:- ọna yóò la fún ee nibi tii kosi ona

Bíi obalala pe oun fii oju kò òwu alantakun nii gbogbo igba loju ala .
Itumo:- ijakule nii

Ibi ala kala ni won ti gba ogo ati arisiki awọn kan ti won kan wa laye bi alaisi

Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/WhatsApp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

★ ★Bami share post yi fun anfani opo eniyan ogun aye koni bori re amin.Ọlọhun  toda gbogbo wa mọ nkan ti owulo fún wa bẹ...
21/07/2026

★ ★

Bami share post yi fun anfani opo eniyan ogun aye koni bori re amin.

Ọlọhun toda gbogbo wa mọ nkan ti owulo fún wa bẹ sini kosi eniti owá láyé tii koni iṣoro sugbon isoro wa kole papo tori wipe kadara ti oni kaluku wa gbewa si aye otooto ni.

Ẹjẹki a sọrọ nípa ọmọ ajé
Ọpọlọpọ ẹda nii ko mọ pé ọmọ ajé níí oun ṣugbọn ni ipàṣẹ Aini àkíyèsí níí okunfa ti ajé ara-re ko fi wúlò fún e.

Bíi oba ùn se akiyesi awọn nkan wọn yìí ọmọ ajé níí ee

*Bíi oba ba eyan dúró síi idi ọja tii osi un ta daada ṣugbọn bíi iwọ ba duro sí ìdí ọja toje ti ee kòni sí ọjà.

*Àkíyèsí*
Gbiyanju lati ṣe awari ara-re nipasẹ ajé arare kini ohun tofe

*Ọmọ ajé ma ùn nii iṣoro ọkọ tàbí àyà ṣugbọn ọkunrin tabi obinrin ti oba fẹ wọn yóò nii àṣeyọrí ni won igba toba dawan mon.

*Ọmọ ajé ma ùn nii ìpinnu ṣugbọn bíi wọn bá {careless} nkan wọn yìí kii ùn bọ sí amò bíi wọn bá níí akiyesi ati amojuto lori oro aye wan ọna abayọ yóò ṣẹlẹ si won

*Ọmọ ajé ma ùn nii iṣoro lori ọmọ bíbí ni torí pé ajé arawọn kii ùn níí ọmọ púpọ tori won ki yan ipin omo pupo waye

*ọmọ ajé ma ùn bínú abiju nítorí ìgbéraga tiwa ninu ajé won eleyi silefa ki aje fiwan sile lo lojiji.

*Ọmọ ajé ma ùn ni ikorira ọkunrin nitori eyi ti won bati jaja feran ju toba ti da won won kii feran okunrin kankan mon.

*Ọmọ ajé kii ùn bímọ ju meji tabi ẹyọkan lọ owa pọju meta.

Sugban eyi tobati se oyun ri ninu wan leyin ti oba bi omo meji tabi meta ikan ninun awan omo yi ma fi won si áyé eleyi ni ijiya ti awan egbe ma fida seria fun tabi ki won gba oko lowo re lojiji tabi ki wan ma tete ri omo bi leyin igbeyawo

*Ọkọ ti obafe ọmọ ajé ma ùn nii owó ṣùgbọ́n wọn kii ùn duro lori ìyàwó kan. Iwo okunrin ti awon omo Aje yi koba fowo si won le gba owo re abi kiwon gba ikan omokunrin re sora dada omo aje legba ki oko oun ni ale sugban koni gba ki ofe iyawo le oun

*Ọkùnrin ọmọ ajé kii ùn tètè ríi àyà fẹ tori wipe egun egun idile maun da opo wan laamun.

ogun ile baba kije ki omo aje lokunrin tete ri ogo wan lo omo aje kogbodo se eru labe eniyan eewo ni.

* Ọmọ ajé ma ùn nifẹ ọkọ wọn tabi aya wan ṣugbọn ọkọ tabi aya wan kii ùn nife wọn dáadáa.

Wọn jẹ iseda ti o ma ùn jowu púpọ bẹ sini ara gbigbona ma ùn da wahala sinu relationship won.

Ẹjẹki ASE àwárí iru ẹnití a jẹ kii a m'aba wáyé asán.

*IGBA ÀJÉ*

Mofi akoko yi bẹ iwọ iranse aje ti oni igba aje nii ọwọ tàbí nii ese jowo mase jeki Ebun yi fi ọ silẹ nítorí púpò nínú iseda yin kii un fi bẹ nii itelorun oun gbogbo ayafi igbati anfani yi ba bọ mọ wọn lọwọ nii oju wọn tó má un walẹ

Igba aje jẹ nkan pataki tii oniṣe pẹlu isemi okun besini sasa nii gbogbo ipin irawọ tii kii un ní sugbon báwo nii asele mọ ìwúlò igba aje ninu aiye wa

*ÌWÚLÒ IGBA ÀJÉ*

*Igba aje má un fini lọkàn balẹ latileje kii ogo ati ọla arawa buyo ni won ba igbati abati unse amulo rẹ

Igba aje má un wa ni owo otun gbogbo onirawo omi sugbon diẹ ninu wọn kìí sábà tete fura

Igba aje má un wa nii isalẹ ahọn gbogbo onirawo INÁ sugbon púpọ ninu wọn nii oma un fi ọrọ ẹnu koba ara rẹ idi niyi ti idamu má ùn fi jọba nínú ayé púpọ ninu wọn

Igba aje má ùn wa nii gigirise onirawo erupe nitori adamo ipin iseda irawọ wọn nii opese anfani yìí fún wọn ṣugbọn níwọ̀nba igbati obati ùn rin ìrìn òru tabi oun fi ese (leg) lasan te ori erupe laiwo bata igba aje yi kole wulo fun e.

Idi niyi ti mofi maun so fun wa ni gbogbo igba wipe eje kase awari ara wa lati mo iru eda ti aje ai se awari ara re loun fa ogun sinu aye re kii se ota tabi ogun idile loun dae laamu iwo gan gan ni isoro aye ara re.

Igba aje má ùn wa ni ẹgbẹ ejika otun onirawo afẹfẹ tobaje elere omo agaga okunrin idi niyi tii kofi dara kii onirawo yi l'ọkunrin masun sì ẹgbẹ ògiri ni gbogbo igba

Ọpọlọpọ nii oti fi aimọkan baye ara re je ti igba aje rẹ ti fo besini Aini akiyesi nigba miran má ùn bá igba aje ẹda eniyan je

*NJE BAWO NII IGBA AJE WA SELE WÚLÒ FUN WA?*

Bẹẹni iru eniti igba aje ee ba ùn kìlọ fún pe kolo ohun daada nii ỌWỌ OTUN ATI ATẸLẸSẸ OTUN ma ùn yun nii gbogbo igba sugban ti koba tete gbe igbese lori e igba aje yi ma kuro ni ara re laipe.

*NJE BII OMO ARÁYÉ BATI LO DIE KURO NINU IGBA ÀJÉ EDA TABI IWO GAN GAN TI SE AFOWOFA TI IGBA AJE YI TI KURO NI ARA RE TABI AWAN IKA ENIYAN TI PA AJE YI MO Ẹ LARA SE ỌNÀ ABAYỌ WA FÚN* ? BENI ONA ABAYO WA.

Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritual and physical
👇
Call/WhatsApp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

21/07/2026

★ ★

INGREDIENTS
👇🏻
● Stonebreaker (Phyllanthus niruri) leaves – 2 handfuls
● Pawpaw leaves – 1 medium leaf
● Fresh turmeric – 1 thumb-sized piece
● Water – 1.5 litres

PREPARATION
👇🏻
1. Wash all herbs properly.
2. Cut the pawpaw leaves and turmeric into small pieces.
3. Boil everything in 1.5 litres of water for 15 minutes.
4. Allow it to cool and strain.

Dosage
● Take ½ cup (120–150 mL)
● 3 times daily, preferably before meals.
● Use for 4 weeks,

Tested and confirmed ✅

Call/WhatsApp
👇🏻
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

★ ★Ki ama ṣe iṣẹ yi ni àrááró tí aba tiun losi ìdí òkòwò (business) wa iyò òkun (sea salt 🧂)Oyin Gidi (original honey 🍯 ...
20/07/2026

★ ★

Ki ama ṣe iṣẹ yi ni àrááró tí aba tiun losi ìdí òkòwò (business) wa

iyò òkun (sea salt 🧂)
Oyin Gidi (original honey 🍯 )

*ṢÍṢE RẸ*
👇🏻
Ào bú iyọ òkun yi sí atẹlẹ ọwọ́ òsi wá ào tẹ éjì ogbè síi ào bú oyin gidi sí ojú àwọn éjì ogbe yi.

Pẹlu àdúrá ào dà iyọ yí sí ẹnu ọnà ào tẹẹ mọlẹ jáde, èyí toba kú ní ọwọ wà ào fi ra orí wa,

*ÀKÍYÈSÍ*
👇🏻
ojoojumọ ní ào má ṣe iṣẹ yí ti àbá tiun lọsí ìdí òkòwò (business) wà

*TESTED AND CONFIRM ✅*

Fún àtúnṣe lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇
Call/Whatsapp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

★ ★àgbàdo fúnfún ào sèé jìná ào gé agbọn sí órí é ào bù oyin ati sugar le lórí ào fi se sára fún àwọn ọmọdé pẹlu àdúrá n...
17/07/2026

★ ★

àgbàdo fúnfún ào sèé jìná ào gé agbọn sí órí é ào bù oyin ati sugar le lórí ào fi se sára fún àwọn ọmọdé pẹlu àdúrá ni ọjọ àséyọrí wa.

Fún Itọni lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇
Call/Whatsapp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

★ ★Sara yi dára púpọ̀ pàtàkì jùlọ fún ẹni tí ìṣòro ayé rẹ kobaiti wo grade one Gégé bí àlàyé ti momaun se fún wá wípé àw...
16/07/2026

★ ★

Sara yi dára púpọ̀ pàtàkì jùlọ fún ẹni tí ìṣòro ayé rẹ kobaiti wo grade one

Gégé bí àlàyé ti momaun se fún wá wípé àwon ìṣòro kàn wá tojẹ wípé oti kọja ọrọ sara

Ti ẹda bati wà nínú ìṣòro yi kofi odidi erin (elephant) se sára òun waist àsìkò ara rẹ ni

Kìí se gbogbo ìsòro ni agbára sara ka lati yanju, má wò ayé rẹ niran ti yofi bajẹ tán

Ìṣòro kọọkan lóni ọna abayọ tiẹ, fún ìdí èyí tí ìṣòro ayé rẹ bati kọja ọrọ sára lọ mójú tó ọrọ ayé rẹ ni.

Má wulẹ máà waist àsìkò ará rẹ lórí sara.

Lọ mójú tó òun toyẹ ki omoju tó ki ìṣòro ayé rẹ lè di òun ìgbàgbé

*ÀWỌN NKÁN TÍ ÀO LỌ WÁ*

👇🏻
ẸSẸ MALU
ÒBÍ FÚNFÚN
OWO #50

ẹsẹ iwájú malu méjèjì tobaje wípé ọkunrin lofẹ se sara yi ào ge sí mésàn

Tobaje wípé obìnrin ní méje ni ama gé sí

Òwo #50 mẹsan fún okùnrin méje fún obìnrin

Òbí fúnfún mẹsan fún okùnrin méje fún obìnrin

Ào fi da iná oúnjẹ fún àwọn ọmọdé ọkunrin ounjẹ abọ mésàn, obìnrin ounjẹ abọ méje.

Ọjọ toba jẹ ọjọ àséyọrí wa ni amà se sara yi.

*ÀKÍYÈSÍ ÀTI ÌKÌLỌ*
👇🏻
oúnjẹ fúnfún ni ágbọdọ lò bí Rice, semo, tuwo, àti bẹẹ bẹẹ lọ, Ao gbọdọ jẹ nínú ounjẹ yí.

Fún Itọni lórí ọrọ ayé rẹ spiritually and physically
👇🏻
Call/Whatsapp
0903 500 4212
Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ

Address

Lagos
EVERYWHERE

Website

Alerts

Be the first to know and let us send you an email when Asiri Irawọ Ẹdá Ati Ọnà Abayọ posts news and promotions. Your email address will not be used for any other purpose, and you can unsubscribe at any time.

Shortcuts

Share