24/09/2026
Alafia fun gbogbo Eyin Eniyan ti E wa ninu Yara yi, 🕊️ ( 🔥🕊️ ) Fun gbogbo Eyin ti E hun wa Ebun Emi Lorisirisi, Bi Ifedefo,Imo ayah, Igba Itumo, igbohun, ati bebe lo,Ti E ti gbinyanju gbinyanju, ti E ti gba awe gba awe ti E ko ri iyato,.. Ewa lo se Eto adura yi, Pelu ase olorun oba Eo si yin olorun logo, Abi Eyin ti E fe dagba si ninu Emi 🔥🕊️,. Mi fe soro poju lori ise Yi, E je ki a lo dan wo, ki a pada wa give testimony...Opolopo Awon eniyan ni won tin bere asiri ise yi lowo mi, private wipe kin fun awon, looto, asiri ise Ebun Emi po Lorisirisi, seal gbigbemi re na wa Lorisirisi, sugbon Eleyi ti mo fi sile yi, tested and confirm ni..A ti yonda asiri yi ri bi odun merin seyin, ti Awon Eniyan si ri ise iyanu Olorun latara re.... Ise na niyi- Ao get Agbon Eyokan (one coconut 🥥) 777 perfume eyokan, Candle yellow Meta, Omi Aifohun 💦 (Water you fetch without speaking with any one) Omi inu Apata 💦(Water you inside Rock 🪨) Omi Okun 💦🌊(Sea Water), Iyo die, efun ibile tabi chalk white, Pelu empty Bottle kan..O le je igo tabi plastic... Sise re - AO Jo omi inu agbon yi lati oju re, meteta, sinu abo kan, ao wa ro sinu empty Bottle Yi, leyin na ao da awon omi yoku mo, ao wa fi perfume 777 die si inu re,.. Ao gbe iyoku kale, Ao wa bu iyo sile le, Ao gbe ise ti a ro sinu bottle yi le lori, Ao wa fi efun ibile tabi chalk white ko oruko Mimo Meteta yi sile, - ELI WAKUKU, EFULI-FULI YAH, ELI AROJAH, ni igba kokan, ao ko ni triangle 📐 form ti won ma kan ara won, yi ise ti a gbe kale yi ka,. Ao wa tan ina si awon candle meteta 🕯️ yi ni igun kokan , Ao wa fi perfume 777 yi si ara wa, ao tun fi si gbogbo ayika ibi ti a ti fe gba Adura na,.. Ti a ba ri Turari na, E je ki a fin.. Ao wa ka psalms:51(1*), Psalms:19 (7*) , Isaiah:6vs1-8(7*), Act2vs1-4(7*), Revelation:4(1*), Ao wa pe Awon oruko mimo yi si - (7*) (7*) (7*) (7*) (7*) (7*) Ao wa gbadura si ise yi dada, Fun Ebun Emi Lorisirisi, ati Akotun agbara imisi ijinle ..ati gbogbo Inkan ti a ba fe.. ko ju bayi lo.. Lilo re.- Ao ma mun ise yi ni fun ojo meta pere.. AO si ma fi perfume 777 yi si ara wa ni o,.. Ise ti o daju gidi gan ni o..Nb:Pelu awe funfun ojo kan ni ise yi o, Ojo Wednesday ni o dara lati ma se ise yi,..Ago Meta ni Ao bere adura yi.. Fun gbogbo Eyin ti E o ba se ise yi, E ri daju wipe E Comment lati dupe ki E si share post yi kakiri fun anfani Elominran, yio si je fun gbogbo Eyin ti E ba se be pelu ase olorun oba,Eo si ni Eri ayo... Eyin ti E ba fe ki a ba wa se ise yi, tabi eyikeyi Eto adura miran E message mi nibi tabi Whatsapp @08063529338 🕯️ E lo follow mi bayi nibi Woli Joseph Adesojii
Alafia fun gbogbo Eyin Eniyan ti E wa ninu Yara yi, 🕊️ ( 🔥🕊️ ) Fun gbogbo Eyin ti E hun wa Ebun Emi Lorisirisi, Bi Ifedefo,Imo ayah, Igba Itumo, igbohun, ati bebe lo,Ti E ti gbinyanju gbinyanju, ti E ti gba awe gba awe ti E ko ri iyato,.. Ewa lo se Eto adura yi, Pelu ase olorun oba Eo si yin olorun logo, Abi Eyin ti E fe dagba si ninu Emi 🔥🕊️,. Mi fe soro poju lori ise Yi, E je ki a lo dan wo, ki a pada wa give testimony...Opolopo Awon eniyan ni won tin bere asiri ise yi lowo mi, private wipe kin fun awon, looto, asiri ise Ebun Emi po Lorisirisi, seal gbigbemi re na wa Lorisirisi, sugbon Eleyi ti mo fi sile yi, tested and confirm ni..A ti yonda asiri yi ri bi odun merin seyin, ti Awon Eniyan si ri ise iyanu Olorun latara re.... Ise na niyi- Ao get Agbon Eyokan (one coconut 🥥) 777 perfume eyokan, Candle yellow Meta, Omi Aifohun 💦 (Water you fetch without speaking with any one) Omi inu Apata 💦(Water you inside Rock 🪨) Omi Okun 💦🌊(Sea Water), Iyo die, efun ibile tabi chalk white, Pelu empty Bottle kan..O le je igo tabi plastic... Sise re - AO Jo omi inu agbon yi lati oju re, meteta, sinu abo kan, ao wa ro sinu empty Bottle Yi, leyin na ao da awon omi yoku mo, ao wa fi perfume 777 die si inu re,.. Ao gbe iyoku kale, Ao wa bu iyo sile le, Ao gbe ise ti a ro sinu bottle yi le lori, Ao wa fi efun ibile tabi chalk white ko oruko Mimo Meteta yi sile, - ELI WAKUKU, EFULI-FULI YAH, ELI AROJAH, ni igba kokan, ao ko ni triangle 📐 form ti won ma kan ara won, yi ise ti a gbe kale yi ka,. Ao wa tan ina si awon candle meteta 🕯️ yi ni igun kokan , Ao wa fi perfume 777 yi si ara wa, ao tun fi si gbogbo ayika ibi ti a ti fe gba Adura na,.. Ti a ba ri Turari na, E je ki a fin.. Ao wa ka psalms:51(1*), Psalms:19 (7*) , Isaiah:6vs1-8(7*), Act2vs1-4(7*), Revelation:4(1*), Ao wa pe Awon oruko mimo yi si - (7*) (7*) (7*) (7*) (7*) (7*) Ao wa gbadura si ise yi dada, Fun Ebun Emi Lorisirisi, ati Akotun agbara imisi ijinle ..ati gbogbo Inkan ti a ba fe.. ko ju bayi lo.. Lilo re.- Ao ma mun ise yi ni fun ojo meta pere.. AO si ma fi perfume 777 yi si ara wa ni o,.. Ise ti o daju gidi gan ni o..Nb:Pelu awe funfun ojo kan ni ise yi o, Ojo Wednesday ni o dara lati ma se ise yi,..Ago Meta ni Ao bere adura yi.. Fun gbogbo Eyin ti E o ba se ise yi, E ri daju wipe E Comment lati dupe ki E si share post yi kakiri fun anfani Elominran, yio si je fun gbogbo Eyin ti E ba se be pelu ase olorun oba,Eo si ni Eri ayo... Eyin ti E ba fe ki a ba wa se ise yi, tabi eyikeyi Eto adura miran E message mi nibi tabi Whatsapp @08063529338 🕯️ E lo follow mi bayi nibi - WoliJoseph Adesoji Baba Imole